Ameyo Adadevoh
Ìrísí
Ameyo Adadevoh | |
---|---|
Ìbí | Ameyo Stella Adadevoh 27 Oṣù Kẹ̀wá 1956 Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà |
Aláìsí | 19 August 2014 Èkó , Nàìjíríà | (ọmọ ọdún 57)
Ọmọ orílẹ̀-èdè | ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà |
Ilé-ẹ̀kọ́ | First Consultant Medical Centre |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Lagos (MBBS) University of London (Endocrinology) |
Ameyo Stella Adadevoh (tí a bí ní ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù Kẹ̀wá ọdún 1956 tí ó sì fi ayé sílè ní ọjọ́ kàndínlọ́gún oṣù kẹjọ ọdún 2014) jẹ́ onímọ̀ ìṣẹ́gun òyìnbó ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Àwọn ènìyàn ma ń ròyìn rẹ̀ fún ipa tí ó kó nínú mímú owó ààrùn Ebola Virus balẹ̀ ní Nàìjíríà nípa mímú ẹni àkọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ ní ààrùn náà, Patrick Sawyer, sí ibi ìpamọ́ bí ó tilè jẹ́ wípé àwọn ìjọba Làìbéríà tako fí fi Patrick sí ìpamọ́.[1][2][3] Ní ọjọ́ kẹrin oṣù kẹjọ ọdún 2014, ìwádìí àyẹ̀wò fihan pé ààrùn Ebola wà lára rẹ̀, àwọn onímọ̀ ìṣẹ́gun sì bẹ̀rẹ̀ ìtójú fún lé sẹ̀kẹ́sẹ̀.[4] Ṣùgbọ́n Adadevoh fi ayé sílè ní ọ̀sán ọjọ́ kan dínlógún oṣù kẹjọ ọdún 2014.[5][1] Ó fi ọkọ rẹ̀, Afolabi àti ọmọ rẹ̀, Bankole sílè sáyé.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 Tolu Ogunlesi (20 October 2014). "Dr Stella Ameyo Adadevoh: Ebola victim and everyday hero". The Guardian (United Kingdom). https://www.theguardian.com/lifeandstyle/womens-blog/2014/oct/20/dr-stella-ameyo-adadevoh-ebola-doctor-nigeria-hero.
- ↑ "Tributes to Dr Ameyo Stella Adadevoh". ThisDaylive. 26 August 2014. Archived from the original on 2014-08-21. https://web.archive.org/web/20140821044034/http://www.thisdaylive.com/articles/tributes-to-dr-ameyo-stella-adadevoh-/186846/.
- ↑ "Dr. Stella Ameyo Adadevoh: A True Patriot". The Street Journal. 20 August 2014. Archived from the original on 3 August 2018. Retrieved 24 August 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Afolabi Sotunde (4 August 2014). "Lagos sees second Ebola case, doctor who treated victim: health minister". Reuters. https://www.reuters.com/article/us-health-ebola-nigeria-idUSKBN0G413H20140804.
- ↑ Kolapo Olapoju (19 August 2014). "Dr Ameyo Adadevoh succumbs to Ebola Virus Disease". Ynaija.com. Archived from the original on 21 August 2014. Retrieved 20 August 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)