Amin Yop Christopher
Ìrísí
Amin Yop Christopher (tí a bí ní ọjọ́ kefà, osù kejìlá, ọdún 1993) jẹ́ ọmọ orílè-èdè Naijiria tó ń gbá bọ́ọ̀lù badminton.[1] Ó ti kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìdíje ní ilè yìí àti nilẹ̀ òkèrè. Ó gbégbá orókè nínú ìdíje Rabat ti ilẹ̀ Africa tó wáyé ní ọdún 2019, ní Casablanca, ní Morocco.[2][3]
Àwọn àṣeyọrí rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìdíje ti ilẹ̀ Africa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àdàpọ̀
Year | Venue | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
2019 | Alfred Diete-Spiff Centre, | Chineye Ibere | Dorcas Ajoke Adesokan | 14–21, 22–20, 17–21 | Silver |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Player: Amin Yop Christopher". bwfbadminton.com. Badminton World Federation. Retrieved 5 July 2020.
- ↑ Shittu, Mudashiru (30 August 2019). "2019 African Games: Nigeria Badminton Scorecard". wildflowers.com.ng. Archived from the original on 5 July 2020. Retrieved 5 July 2020.
- ↑ Shittu, Mudashiru (30 August 2019). "2019 African Games: Nigeria Badminton Scorecard". wildflowers.com.ng. Archived from the original on 5 July 2020. Retrieved 5 July 2020.