Jump to content

Uchechukwu Deborah Ukeh

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Uchechukwu Deborah ukeh (tí a bí ní ọjọ́ kejìlá, oṣù kọkànlá, ọdún 1996) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria tó ń gbá bọ́ọ̀lù badminton.[1] Níọdún 2014, ó kópa nínú ìdíje ti Africa Youth Games, ó sì gbé ipò àkọ́kọ́ ní èẹ̀meejì.[2] Ní ọdún 2016, òun ló gbégbá orókè ní ìdíje gbogboogbò tí ó wáyé ní Ivory Coast, ó sì tún gbéipò akọ́kọ́ nígbà tí ó fọwọsowọpọl pẹ̀lú Gideon Babalola.[3] Ní ọdún 2017, òun àti Babalola dé ipò akọ́kọ́ nínú ìdíje gbogboogbò ti Ivory Coast, àmọ́, ó gbé ipò kejì.[4] Ní ìdíje gbogboogbò tó wáyé ní Benin, Ukeh, tún gbé ipò kìíní.[5] Ní ìdíje tó wáyé ni Naijiria, ti Katsina Golden Star Badminton Championships, Ukeh náà ló ṣe aṣojú Ipinle Edo, òun náà ló gbégbá orókè.[6]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìdíje ilẹ̀ Africa

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìdàpọ̀ àwọn obìnrin

Year Venue Partner Opponent Score Result
2019 Ain Chock Indoor Sports Center,

Casablanca, Morocco

Nàìjíríà Dorcas Ajoke Adesokan Ẹ́gíptì Doha Hany

Ẹ́gíptì Hadia Hosny

9–21, 16–21 Silver Silver

Ìdíje ilẹ̀ Africa

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìdàpọ̀ àwọn obìnrin

Year Venue Partner Opponent Score Result
2019 Alfred Diete-Spiff Centre,

Port Harcourt, Nigeria

Nàìjíríà Dorcas Ajoke Adesokan Nàìjíríà Amin Yop Christopher

Nàìjíríà Chineye Ibere

21–14, 20–22, 21–17 Gold Gold
2020 Cairo Stadium Hall 2,

Cairo, Egypt

Nàìjíríà Dorcas Ajoke Adesokan Ẹ́gíptì Doha Hany

Ẹ́gíptì Hadia Hosny

14–21, 17–21 Silver Silver

Ìdíje fún àwọn ọ̀dọ́ Africa

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìdàpọ̀ àwọn obìnrin

Year Venue Partner Opponent Score Result
2014 Otse Police College,

Gaborone, Botswana

Nàìjíríà Usman Isiaq Gúúsù Áfríkà Bongani von Bodenstein

Gúúsù Áfríkà Anri Schoones

14–21, 21–19, 14–21 Bronze Bronze

Ìdíje gbogboogbò ti BWF

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn obìnrin nìkan

Year Tournament Opponent Score Result
2016 Ivory Coast International Sri Lanka Lekha Shehani 11–21, 14–21 Runner-up
2017 Benin International Nàìjíríà Dorcas Ajoke Adesokan 7–21, 18–21 Runner-up

Ìdàpọ̀ àwọn obìnrin

Year Tournament Partner Opponent Score Result
2013 Nigeria International Nàìjíríà Augustina Ebhomien Sunday Nàìjíríà Tosin Damilola Atolagbe

Nàìjíríà Fatima Azeez

21–18, 21–13 Winner
2017 Benin International Nàìjíríà Peace Orji Nàìjíríà Dorcas Ajoke Adesokan

Nàìjíríà Tosin Atolagbe

18–21, 21–16, 12–21 Runner-up
2019 Ghana International Nàìjíríà Dorcas Ajoke Adesokan Índíà K. Maneesha

Índíà Rutaparna Panda

11–21, 11–21 Runner-up

Ìdàpọ̀ àwọn obìnrin

Year Tournament Partner Opponent Score Result
2016 Ivory Coast International Nàìjíríà Gideon Babalola Benin Tobiloba Oyewole

Benin Xena Arisa

21–7, 21–10 Winner
2017 Ivory Coast International Nàìjíríà Gideon Babalola Nàìjíríà Enejoh Abah

Nàìjíríà Peace Orji

Walkover Runner-up

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Players: Uchechukwu Deborah Ukeh". Badminton World Federation. Retrieved 2 December 2016. 
  2. "AYG: Team Nigeria bags 12 gold". Vanguard. Retrieved 13 November 2017. 
  3. "Internationaux de Côte d’Ivoire – Résultats". Association Francophone de Badminton (in Èdè Faransé). Archived from the original on 14 November 2017. Retrieved 13 November 2017. 
  4. "Internationaux Séniors de Badminton : Le Nigeria rafle 11 médailles !" (in Èdè Faransé). Regionale.info. Retrieved 13 November 2017. 
  5. "Nigeria's Badminton Team Wins Benin Republic International". Sports Village Square. Retrieved 13 November 2017. 
  6. "Krobakpor, Adesokan rule Katsina Badminton Championships". GongNews. Archived from the original on 14 November 2017. Retrieved 13 November 2017.