Jump to content

Fatima Azeez

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Titilayo Fatima Azeez (tí a bí ní ọjọ́ kọkànlelógún, osú kejìlá, ọdún 1992) jẹ́ agbá bọ́ọ̀lù badminton ti orílè-èdè Naijiria.[1] Ní ọdún 2010, ó parí Summer Youth Olympics ní Singapore.[2] Ní ọdún 2011, ó jẹ èbùn ti All-Africa Games ní Maputo, Mozambique.[3]

Àwọn àṣeyọrí rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìdíje àwọn obìnrin méjì

Year Venue Partner Opponent Score Result
2011 Escola Josina Machel,

Maputo, Mozambique

NàìjíríàGrace Daniel Seychelles Camille Allisen

Seychelles Cynthia Course

22–24, 15–21 Bronze Bronze

Ìdíje ti ilẹ̀ Africa

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Obìnrin ọ̀wọ́ kan nìkan

Year Venue Opponent Score Result
2012 Arat Kilo Hall, Addis Ababa, Ethiopia Nàìjíríà Grace Gabriel Ofodile 19–21, 21–14, 16–21 Silver Silver

Obìnrin ọ̀wọ́ méjì

Year Venue Partner Opponent Score Result
2014 Lobatse Stadium,

Gaborone, Botswana

Nàìjíríà Tosin Damilola Atolagbe Mauritius Kate Foo Kune

Mauritius Yeldy Louison

16–21, 23–21, 17–21 Bronze Bronze

Ìdíje àgbáyé ti BWF

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Obìnrin ọ̀wọ́ kan nìkan

Year Tournament Opponent Score Result
2013 Nigeria International Nàìjíríà Tosin Damilola Atolagbe 21–16, 15–21, 22–20 Winner

Women's doubles

Year Tournament Partner Opponent Score Result
2014 Nigeria International Nàìjíríà Tosin Atolagbe Ùgándà
Shamim Bangi
Ẹ́gíptì Hadia Hosny
5–11, 10–11, 10–11 Runner-up
2014 Lagos International Nàìjíríà Tosin Atolagbe Nàìjíríà Dorcas Adesokan

Nàìjíríà Maria Braimoh

19–21, 20–22 Runner-up
2014 Uganda International Nàìjíríà Tosin Atolagbe Nàìjíríà Dorcas Adesokan

Nàìjíríà Augustina Sunday

14–21, 21–9, 21–12 Winner
2013 Nigeria International Nàìjíríà Tosin Atolagbe Nàìjíríà Augustina Sunday

Nàìjíríà Deborah Ukeh

18–21, 13–21 Runner-up

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]