Maria Braimoh
Ìrísí
Maria Hajara Braimoh (tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlógún, oṣù kìíní, ọdún 1990) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria tó ń gbá Badminton.[1] Ó wà lára àwọn ẹgbẹ́ ti Nàìjíríà tó gbá Badminton ní ọdún 2007 àti ìdíje gbogboogbò ti ilẹ̀ Afrika ní ọdún 2011. Braimoh tún kópa nínú ìdíje ti Commonwealth tí wọ́n ṣe ní odún 2010, ní New Delhi, India.[2]
Àwọn àṣeyọrí rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìdíje gbogboogbò ti ilẹ̀ Afrika
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn obìnrin nìkan
Year | Venue | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|
2011 | Escola Josina Machel, Maputo, Mozambique | Susan Ideh | 12–21, 21–19, 7–21 | Bronze |
Àdàpọ̀ àwọn obìnrin
Year | Venue | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
2015 | Gymnase Étienne Mongha, | Grace Gabriel | Juliette Ah-Wan | 13–21, 16–21 | Bronze |
Àwọn olúborí ilẹ̀ African
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn obìnrin nìkan
Year | Venue | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|
2010 | Kampala, Uganda | Stacey Doubell | 18–21, 17–21 | Bronze |
Àdàpọ̀ àwọn obìnrin
Year | Venue | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
2011 | Marrakesh, Morocco | Susan Ideh | Annari Viljoen | 9–21, 16–21 | Silver |
2010 | Kampala, Uganda | Susan Ideh | Annari Viljoen | 6–21, 6–21 | Silver |
Ìdíje gbogboogbò ti BWF
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àdàpọ̀ àwọn obìnrin
Year | Tournament | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
2015 | Nigeria International | Grace Gabriel | Cemre Fere | 14–21, 14–21 | Runner-up |
2014 | Laagos International | Dorcas Ajoke Adesokan | Tosin Damilola Atolagbe | 21–19, 22–20 | Winner |
2010 | Kenya International | Susan Ideh | Annari Viljoen | 10–21, 21–12, 10–21 | Runner-up |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Players: Braimoh Maria". bwfbadminton.com. Badminton World Federation. Retrieved 2 December 2016.
- ↑ "Braimah Maria Hajara". cwgdelhi2010.infostradasports.com. New Delhi 2010. Archived from the original on 2 December 2016. Retrieved 2 December 2016.