Jump to content

Susan Ideh

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Susan Funaya Ideh (tí a bí ní ojọ́ karùn-ún, oṣù karùn-ún, ọdún 1987) jẹ́ ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà tó ń gbá bọ́ọ̀lù badminton.[1] Ó kópa nínú ìdíje ti Commonwealth tó wáyé ní ọdún 2010, ní New Delhi, ní orílẹ̀-èdè India.[2] Ní ọdún 2015, ó gbapò kìíní ní ìdíje gbogboogbò ti ilè Africa, ní Maputo, ní Mozambique.[3]

Àwọn àṣeyọrí rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìdíje gbogboogbò ti ilè Africa

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn obìnrin nìkan

Year Venue Opponent Score Result
2011 Escola Josina Machel, Maputo, Mozambique Nàìjíríà Grace Gabriel 21–16, 21–19 Gold Gold

Àdàpọ̀

Year Venue Partner Opponent Score Result
2007 Salle OMS El Biar,

Algiers, Algeria

Nàìjíríà Grace Daniel Gúúsù Áfríkà Michelle Edwards

Gúúsù Áfríkà Chantal Botts

12–21, 21–9, 20–22 Silver Silver
2003 Indoor Sports Halls National Stadium,

Abuja, Nigeria

Nàìjíríà Grace Daniel Gúúsù Áfríkà Michelle Edwards

Gúúsù Áfríkà Chantal Botts

Silver Silver

Àdàpọ̀

Year Venue Partner Opponent Score Result
2003 Indoor Sports Halls National Stadium,

Abuja, Nigeria

Nàìjíríà Abimbola Odejoke Gúúsù Áfríkà

Gúúsù Áfríkà

Bronze Bronze

Ìdíje ti ilẹ̀ Africa

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Obìnrin nìkan

Year Venue Opponent Score Result
2012 Arat Kilo Hall, Addis Ababa, Ethiopia Nàìjíríà Fatima Azeez 16–21, 11–21 Bronze Bronze
2011 Marrakesh, Morocco Gúúsù Áfríkà Stacey Doubell 21–17, 18–21, 13–21 Bronze Bronze
2009 Nairobi, Kenya Seychelles Juliette Ah-Wan 17–21, 21–17, 12–21 Bronze Bronze
2004 Beau Bassin-Rose Hill, Mauritius Gúúsù Áfríkà Chantal Botts 9–11, 0–11 Bronze Bronze

Àdàpọ̀

Year Venue Partner Opponent Score Result
2012 Arat Kilo Hall, Addis Ababa, Ethiopia Nàìjíríà Grace Daniel Gúúsù Áfríkà Annari Viljoen

Gúúsù Áfríkà Michelle Edwards

16–21, 19–21 Silver Silver
2011 Marrakesh, Morocco Nàìjíríà Maria Braimoh Gúúsù Áfríkà Annari Viljoen

Gúúsù Áfríkà Michelle Edwards

9–21, 16–21 Silver Silver
2010 Kampala, Uganda Nàìjíríà Maria Braimoh Gúúsù Áfríkà Annari Viljoen

Gúúsù Áfríkà Michelle Edwards

6–21, 6–21 Silver Silver

Àdàpọ̀

Year Venue Partner Opponent Score Result
2012 Arat Kilo Hall, Addis Ababa, Ethiopia Nàìjíríà Ola Fagbemi Gúúsù Áfríkà Dorian James

Gúúsù Áfríkà Michelle Edwards

18–21, 17–21 Bronze Bronze

Ìdíje gbogboogbò ti BWF

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Obìnrin nìkan

Year Tournament Opponent Score Result
2009 Kenya International Ẹ́gíptì Dina Nagy 8–21, 16–21 Runner-up

Àdàpọ̀

Year Tournament Partner Opponent Score Result
2010 Kenya International Nàìjíríà Maria Braimoh Gúúsù Áfríkà Annari Viljoen

Gúúsù Áfríkà Michelle Edwards

10–21, 21–12, 10–21 Runner-up
2009 Mauritius International Seychelles Juliette Ah-Wan Mauritius Shama Aboobakar

Mauritius Amrita Sawaram

21–18, 21–17 Winner

Àdàpọ̀

Year Tournament Partner Opponent Score Result
2015 Nigeria International Nàìjíríà Olorunfemi Elewa Ghánà Daniel Sam

Ghánà Gifty Mensah

21–19, 21–17 Winner
2014 Nigeria International Nàìjíríà Jinkan Ifraimu Nàìjíríà Ola Fagbemi

Nàìjíríà Dorcas Ajoke Adesokan

8–11, 11–4, 7–11, 11–10, 11–8 Winner
2011 Botswana International Nàìjíríà Ola Fagbemi Gúúsù Áfríkà Dorian James

Gúúsù Áfríkà Michelle Edwards

16–21, 21–11, 19–21 Runner-up
2010 Kenya International Nàìjíríà Jinkan Ifraimu Gúúsù Áfríkà Wiaan Viljoen

Gúúsù Áfríkà Annari Viljoen

12–21, 10–21 Runner-up

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Players: Susan Ideh". bwfbadminton.com. Badminton World Federation. Retrieved 2 December 2016. 
  2. "Ideh Susan". cwgdelhi2010.infostradasports.com. New Delhi 2010. Archived from the original on 2 December 2016. Retrieved 2 December 2016. 
  3. "Diários dos X Jogos Africanos: África do Sul e Nigéria repartem Ouro do Badminton" (in pt). @Verdade. Archived from the original on 4 July 2018. https://web.archive.org/web/20180704213617/http://pda.verdade.co.mz/jogos-africanos/22125-diarios-dos-x-jogos-africanos-africa-do-sul-e-nigeria-repartem-ouro-do-badminton. Retrieved 15 January 2018.