Grace Gabriel
Grace Gabriel Ofodile (tí a bí ní ọjó karùndínlọ́gbọ̀n, oṣù kẹfà, ọdún 1988) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria tó ń gbá bọ́ọ̀lù badminton. Ó gbégbá orókè nínú ìdíje gbogboogbò ti ilẹ̀ Áfríkà ti ọdún 2012 àti 2013. Gabriel tún gbégbò keta ní ìdíje ti ilẹ̀ Áfríkà tó wáyé lọ́dún 2011 àti 2015.
Iṣẹ́ rẹ̀ bíi agbábọ́ọ̀lù badminton
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó wà lára àwọn tó kópa nínú ìdíje gbogboogbiò ti ilẹ̀ Africa tó sì gbégbá orókè ní ọdún 2011.[1] Nínú ìdíje ti ilè Africa tó wáyé ní ọdún 2014, ó kọ́pa, ó sì gbé ipò kìíní.[2] Ó tún gba ipò kejì nínú ìdíje gbogboogbò ti ilẹ̀ Africa tó wáyé ní ọdún 2015.[3]
Ní osù kesàn-án, ọdún 2013, ìròyìn fi lélè pé ó wà lára àwọn ènìyàn tíwọ́n yàn fún ètò Road to Rio Program, láti lè ran àwọn agbábọ́ọ̀lù badminton ti ilẹ̀ Africa tó fẹ́ kópa nínú ìdíje Olympic ti ọdún 2016.[4]
Fontys University of Applied Sciences ni ó ti kékọ̀ọ́ gboyè, ó sì ń gbé ní Netherlands.[5]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìdíje gbogboogbò ti ilẹ̀ Africa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Obìnrin nìkan
Year | Venue | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|
2015 | Gymnase Étienne Mongha, Brazzaville, Republic of the Congo | Kate Foo Kune | 13–21, 19–21 | Silver |
2011 | Escola Josina Machel, Maputo, Mozambique | Susan Ideh | 16–21, 19–21 | Silver |
Àdàpọ̀
Year | Venue | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
2015 | Gymnase Étienne Mongha,
Brazzaville, Republic of the Congo |
Maria Braimoh | Juliette Ah-Wan | 13–21, 16–21 | Bronze |
Ìdíje ti ilẹ̀ Africa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Obìnrin nìkan
Year | Venue | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|
2014 | Lobatse Stadium, Gaborone, Botswana | Kate Foo Kune | 14–21, 21–14, 17–21 | Silver |
2013 | National Badminton Centre, Rose Hill, Mauritius | Kate Foo Kune | 25–23, 21–12 | Gold |
2012 | Arat Kilo Hall, Addis Ababa, Ethiopia | Fatima Azeez | 21–19, 14–21, 21–16 | Gold |
2011 | Marrakesh, Morocco | Kerry-Lee Harrington | 18–21, 15–21 | Bronze |
Àdàpọ̀
Year | Venue | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
2020 | Cairo Stadium Hall 2, | Chineye Ibere | Doha Hany | 13–21, 12–21 | Bronze |
Àdàpọ̀
Year | Venue | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
2011 | Marrakesh, Morocco | Enejoh Abah | Willem Viljoen | 13–21, 8–21 | Bronze |
Ìdíje gbogboogbò ti BWF
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Obìnrin nìkan
Àdàpọ̀
Year | Tournament | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
2016 | Uganda International | Ogar Siamupangila | Cemre Fere | 16–21, 17–21 | Runner-up |
2015 | Botswana International | Ogar Siamupangila | Elizaberth Chipeleme | 21–11, 21–17 | Winner[6] |
2015 | Nigeria International | Maria Braimoh | Cemre Fere | 14–21, 14–21 | Runner-up |
2015 | Mauritius International | Ogar Siamupangila | Negin Amiripour | 26–28, 14–21 | Runner-up |
2014 | Botswana International | Elme de Villiers |
Shamim Bangi Ogar Siamupangila
|
21–17, 18–21, 21–18 | Winner |
2014 | Zambia International | Kate Foo Kune | Michelle Butler-Emmett | 17–21, 21–19, 17–21 | Runner-up |
2013 | Botswana International | Yeldie Louison | Elme de Villiers | 13–21, 16–21 | Runner-up |
2013 | Mauritius International | Dorcas Ajoke Adesokan | Elme de Villiers | 15–21, 16–21 | Runner-up |
2013 | Kenya International | Dorcas Ajoke Adesokan |
Shamim Bangi
Margaret Nankabirwa |
21–18, 21–9 | Winner |
2013 | Uganda International | Shama Aboobakar |
Shamim Bangi
Margaret Nankabirwa |
21–13, 18–21, 21–12 | Winner |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ http://www.africa-badminton.com/LondonStats/gabriel_ngr.htm[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "African Badminton Championships: Team Nigeria trashes Zambia | Premium Times Nigeria". 24 April 2014.
- ↑ "South Africa dominate badminton". www.supersport.com. 9 September 2015. Archived from the original on 26 April 2018. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Newsletter du Mois de Septembre 2013 Road to Rio". Africa Badminton. Badminton Confederation Africa. Archived from the original on 5 March 2017. Retrieved 22 March 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Players: Grace Gabriel". bwfbadminton.com. Badminton World Federation. Retrieved 11 January 2018.
- ↑ Lukhanda, Samuel (15 December 2015). "Zambia: Siamupangila Bags Badminton Gold". The Times of Zambia (Ndola) – via allafrica.com.