Jump to content

Anastasia Pavlyuchenkova

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Anastasia Pavlyuchenkova
Анастасия Павлюченкова
Orílẹ̀-èdèRọ́síà Russia
IbùgbéMoscow, Russia
Ọjọ́ìbí3 Oṣù Keje 1991 (1991-07-03) (ọmọ ọdún 34)
Samara, Russian SFSR, Soviet Union
Ìga1.77 m (5 ft 10 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fàDecember 2005
Ọwọ́ ìgbáyòRight-handed (two-handed backhand)
Ẹ̀bùn owó$3,299,695
Ẹnìkan
Iye ìdíje232–138
Iye ife-ẹ̀yẹ5 WTA, 5 ITF titles
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 13 (4 July 2011)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́No. 19 (27 May 2013)
Grand Slam Singles results
Open Austrálíà3R (2011)
Open FránsìQF (2011)
Wimbledon3R (2008, 2010)
Open Amẹ́ríkàQF (2011)
Ẹniméjì
Iye ìdíje115–68
Iye ife-ẹ̀yẹ4 WTA, 8 ITF titles
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 30 (13 May 2012)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́No. 31 (27 May 2012)
Grand Slam Doubles results
Open AustrálíàQF (2013)
Open Fránsì3R (2009)
Wimbledon3R (2010)
Open Amẹ́ríkà2R (2010), (2011)
Last updated on: 27 May 2013.

Anastasia Sergeyevna Pavlyuchenkova (Rọ́síà: Анастасия Сергеевна Павлюченкова, Pípè ní èdè Rọ́síà: [ɑnɑstɑˈsijə.pɑvlʉˈt͡ɕɛnkova]; ẹni tí a bí ní ọjọ́ kẹta,oṣù kéje ọdún 1991) jẹ́ àgbà tenis ará Rosia tí ó gba ife ẹ̀yẹ Grand Slam. Tí ipò rẹ̀ ga jùlọ Lágbàáyé ní ọjọ́ kẹrin oṣù kéje ọdún 2011.