Jump to content

Anderson Akaliro

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Anderson Akaliro jẹ́ olóṣèlú àti aṣofin ní orílè-èdè Nàìjíríà. O ṣojú agbègbè Umuahia North ni ile igbimo asofin ipinle Abia . [1] [2] Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress (APC) ó sì ń sìn gẹ́gẹ́ bí alága ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà lórí ètò ìdájọ́ àti ẹ̀sùn gbogbo ènìyàn. [3] [4]