Angel Unigwe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Angel Unigwe
Ọjọ́ìbíAngel Onyinyechi Unigwe
27 Oṣù Kẹfà 2005 (2005-06-27) (ọmọ ọdún 18)
Lagos, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigeria
Iṣẹ́Actress, model, presenter
Ìgbà iṣẹ́2011 – present

Angel Unigwe (orúkọ àbísọ rẹ̀ ni Angel Onyinyechi Unigwe; tí a bí ní ọjọ́ kẹta-dín-lọ́gbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 2005) jẹ́ òṣèré obìnrin ti ilẹ̀ Nàìjíríà, ó jẹ́ aláfiwé, àti aṣètò tí ó tún ṣe ìfihàn nínú àwọn ìkéde tẹlifísàn olókìkí.

Iṣẹ́ Rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ṣàfimọ̀ sí ilé-iṣẹ́ fíìmù nípasẹ̀ ìyá rẹ̀, Unigwe bẹ̀rẹ̀ bí òṣèré ọmọdé tí ó ṣe àfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ ní ọdún 2015 lẹ́hìn tí ó gba àwọn ipa ní 'Alison's Stand,' járá tẹlifísàn Nàìjíríà olókìkí; àti pé láti ìgbà náà ó ti tẹ̀síwájú láti mú ọkàn àwọn òǹwòrán fíìmù dùn'. [1] Akòròyìn Unigwe ni oníròyìn Nàìjíríà Obaji Akpet.

Àwọn Yíyàn Rẹ̀ Àti Àmì Ẹ̀yẹ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Unigwe ti gbádùn ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn yíyàn àti pé ó ti gba àwọn àmì ẹ̀yẹ lọ́pọ̀lọpọ̀ pẹ̀lú Òṣèré Ọmọdé (Child Actor) ti Ọdún 2019 ní Ààmì Ẹ̀yẹ Intellects Giant; [1] Ó lọlé pẹ̀lú àmì ẹ̀yẹ Best Young/Promising Actor ní ọjọ́ kẹta-dín-lọ́gbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 2019, ní ẹdá ọdún 2019 ti Africa Movie Academy Awards (AMAA) );[2] Òṣèré ọmọdé tí ó dára jùlọ nínú fíìmù kan ní àmì ẹ̀yẹ ọdún 2021 'Best of Nollywood ' (BON) fún ipa rẹ̀ nínú 'Strain'. [1]

Àwọn Ìtọ́ka Sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 1.2 "Angel-Onyi wins child actor award". The Nation Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 5 May 2019. Retrieved 7 November 2021. 
  2. "Winners for di 2019 Africa Movie Academy Awards". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/tori-50176271.