Anthony Enahoro

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Adolor ilu Uromi

Anthony Eromosele Enahoro
Anthony Enahoro
Asoju Ileasofin Naijiria
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1923-07-22)Oṣù Keje 22, 1923
Uromi, Ipinle Edo
AláìsíDecember 15, 2010(2010-12-15) (ọmọ ọdún 87)
Benin City, Ipinle Edo

Anthony Eromosele Enahoro tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù keje ọdún 1923 tí ó papò da ní ọdún ọjọ́ Karùún oṣù Kejìlá ọdún 2010. [1]) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ló jẹ́ akọ̀wé àgbà ẹgbẹ́ ìṣèlú Action GroupIgba Oselu Akoko Naijiria.

Ibè rẹ pẹpẹ ayé e[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Anthony jẹ àkọ́bí ọmọ àgbò lè Onewa ni agbegbe Uromi ni ilu Edo ni naijiria.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ijapo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]