Jump to content

Ìlaòrùn Áfríkà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Apa Ilaoorun Afrika)

Iha tabi Apa Ilaoorun Africa jé ïhà tó sumo apa ilà oòrùn jù, àwon orílè-ede tówà ní ìlà-oòrùn Afrika ní: Tanzania, Kenya, Uganda, Rwanda, Burundi, Eritrea,Ethiopia, Somalia, Comoros, Mauritius, Seychelles, Sudan, Djibouti, Eritrea, Madagascar, Malawi, Réunion, Somaliland, Ìlà-oòrùn Afrika ní olùgbé to sumó 464,911,091 ni 2022 [1]



  1. "Population of Eastern Africa (2022)". Worldometer. 2022-03-24. Retrieved 2022-03-25.