Ọ̀rọ̀ayéijọ́un

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Archeology)
Jump to navigation Jump to search
Ilétíátà ayéijóun ìgbà Romu, ni Alexandria, Egypt

Ọ̀rọ̀ayéijọ́un (Archaeology, tabi archeology lede Geesi lati ede Griiki ἀρχαιολογία, archaiologia – ἀρχαῖος, arkhaios, "ayeijoun"; and -λογία, -logia, "-logy[1]") je agbeka awujo omoniyan, lakoko nipa iwari ati ituyewo asa ohun-ini ati awon data ayika ti won fi seyin, ti ninu won je iseowo, onaikole, onidajuayika ati ojuile asa (eyun akoole oloroayeijoun). Nitoripe oroayeijoun lo orisirisi igbese otooto, o se e gba bi sayensi ati bi awon eko omoniyan,[2] be sini ni Amerika won gba bi eka oroomoniyan,[3] botilejepe ni Europe won gba bi eka-eko to dawa.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Or science, ni ede Griiki atijo.
  2. Renfrew and Bahn (2004 [1991]:13)
  3. Haviland et al. 2010, p. 7,14