Armen Sarkissian

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Dr. Armen Sargsyan
Արմեն Սարգսյան
Sargsyan in 2018
Ààrẹ ilẹ̀ Arméníà 4k
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
9 April 2018
Alákóso ÀgbàKaren Karapetyan (Acting)
Serzh Sargsyan
Karen Karapetyan (Acting)
Nikol Pashinyan
AsíwájúSerzh Sargsyan
5th Prime Minister of Armenia
In office
4 November 1996 – 20 March 1997
ÀàrẹLevon Ter-Petrosyan
AsíwájúHrant Bagratyan
Arọ́pòRobert Kocharyan
Ambassador of Armenia to the United Kingdom
In office
1998 – 8 April 2018
ÀàrẹRobert Kocharyan
Serzh Sargsyan
Alákóso ÀgbàArmen Darbinyan
Vazgen Sargsyan
Aram Sargsyan
Andranik Margaryan
Serzh Sargsyan
Tigran Sargsyan
Hovik Abrahamyan
Karen Karapetyan
Arọ́pòArmen Liloyan (Acting)
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí23 Oṣù Kẹfà 1953 (1953-06-23) (ọmọ ọdún 70)
Yerevan, Armenian SSR, Soviet Union
Ọmọorílẹ̀-èdèArmenian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúIndependent
(Àwọn) olólùfẹ́Nouneh Sarkissian
Àwọn ọmọ2
OccupationPolitician, physicist, computer scientist
Signature

Armen Sargsyan (Arméníà: Արմեն Վարդանի Սարգսյան;[note 1] ọjọ́ìbí 23 June 1953) ni olóṣèlú, onímọ̀físíksì àti onímọ̀sáyẹ́nsì kọ̀mpútà tó ti wà lórí ipò bíi Ààrẹ ilẹ̀ Arméníà láti ọdún 2018.[1] Ó ti kọ́kọ́ wà ní ipò bíi Alákóso Àgbà ilẹ̀ Arméníà láti ọjọ́ 4 oṣù kọkànlá ọdún 1996 títí di ọjọ́ 20 oṣù kẹta ọdún 1997 àti tẹ́lẹ̀ gẹ́gẹ́bí aṣojú ilẹ̀ Arméníà ní Londonu. Wọ́n dìbò yan Sargsyan ní ọjọ́ 2 oṣù kẹta ọdún 2018 ó sì bẹ̀rẹ̀ ìgbà ààrẹ rẹ̀ ní ọjọ́ 9 oṣù kẹrin ọdún 2018.[2]


Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]


Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref> tags exist for a group named "note", but no corresponding <references group="note"/> tag was found