Serzh Sargsyan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Serzh Sargsyan
Սերժ Սարգսյան
Msc 2009-Saturday, 16.00 - 19.00 Uhr-Moerk 002 Sargsyan.jpg
Aare ile Armenia
Lọ́wọ́
Ó bọ́ sí orí àga
9 April 2008
Aṣàkóso Àgbà Tigran Sargsyan
Asíwájú Robert Kocharyan
Alakoso Agba ile Armenia
Lórí àga
26 March 2007 – 9 April 2008
President Robert Kocharyan
Asíwájú Andranik Margaryan
Arọ́pò Tigran Sargsyan
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí 30 Oṣù Kẹfà 1954 (1954-06-30) (ọmọ ọdún 63)
Stepanakert, Nagorno-Karabakh AO Azerbaijan SSR, Soviet Union (now Stepankert, Nagorno-Karabakh Republic)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú Republican Party
Tọkọtaya pẹ̀lú Rita Sargsyan
Alma mater Yerevan State University
Ẹ̀sìn Armenian Apostolic

Serzh Azati Sargsyan (Arméníà: Սերժ Ազատի Սարգսյան, ojoibi June 30, 1954[1]) ni Aare orile-ede Armenia. O bori ninu idiboya Aare Osu Keji 2008[2] o si bo si ori aga ni Osu Kerin 2008.[3] Ko ni ibatan mo Tigran Sargsyan to je Alakoso Agba ile Armenia lowo.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]