Arun HIV/AIDS ni Naijiria

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Prevalence of AIDS in Nigeria from 1991–2010. Includes predictions up to 2016.

Lasiko 2014 ni Naijiria, HIV wopo laarin awon odo to ti balaga to ti to omo odun 15–49[1] je ida 3.17%.[2] Ile Naijiria ni o gbe ipo keji ninu awon ti o n semi pelu arun HIV.[3] Arun HIV  di ajakale ti o si po ju ara won lo ni agbegbe si agbegbe. Lawon ipinle kan, titan kale arun, ni o da lori iwa ati isemi ti o le koko, nigba ti awon itankale re ni awon ipinle miiran da lori ibalopo pelu opo eniyan.[citation needed] Awon odo langba ati awon agbalagba ni won si ko si panpe HIV., tawon odomobinrin ati awon abileko lo wopo ju awon okunrin lo.[4]  Opo iwa lo le sokunfa itankale arun naa, lara awon iwa bee ni: Ise asewo (prostitution), eyi ti o wopo laarin olowo ibalopo (itinerant workers), ti o si ti sokunfa itanka arun   ti a n ko nibi ibalopo (STI), iwa ibalopo Ako si Ako (homosexaual) ati iwa ibalopo olopo ero (heterosexual) , ati iwa fifi awon omobinrin sowo eru lo sile okere, iwa aisamojuto ayewo eje ki a to gbaa tabi funi.[5]

Ile Najiria lati asiko isejoba ologun (military rule) ti o gba orile ede naa kan fun odidi odun meji-dinlogun (28 years) lara odun metadin-logofa (57 years) ti orile ede Naijiria ti gba ominira (independence) ni odun 1960. Ofin ti o de ibaje awulo ko fese mule to. Awujo awa ara wa  (Civil society) ko fese mule lasiko isejoba awon ologun ni orile ede Naijiria. Onka omo ile Naijiria nigba naa nira lati mo paa paa nigba akitiyan ati se ijoba awa arawa lati le fese isejoba ile Naijiria mule (Nigerian government) ko ipalara ba ise deede nipa  eto ilera (health care) kaakiri awon agbegbe orile ede naa. Isakoso awon alakale eto leseese lati ori ijoba apapo, ijoba ipinle si ipinle ati ijoba ibile mu isoro wa lopolopo.  Awon ilese eto ilera ti o je ti aladani ni ko ri amojuto dara dara, paa paa julo ni ko ni ibasepo pelu ilese eto ilera ti ijoba nibi ti eko nipa arun HIV ati imojuto awon eniyan ti kere jojo. Itoju ati iranlowo ko to nkan lati owo awon Dokita ati Noosi, nitori  ise ti po ju won lo.ati wipe won ko ni imo ati eko to peye lati pese eto ilera to yanranti fun awon alaisan naa.[5][citation needed]

E tun le wo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • AIDS pandemic
  • Health care in Nigeria
  • HIV/AIDS in Africa

Awon itoka si[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Definitions and notes" Accessed May 11, 2016.
  2. "HIV/AIDS - adult prevalence rate" CIA World Factbook (2014) Accessed May 11, 2016.
  3. "HIV/AIDS - People Living with HIV/AIDS" CIA World Factbook (2014) Accessed May 11, 2016.
  4. citation needed
  5. 5.0 5.1 "2008 Country Profile: Nigeria". U.S. Department of State. 2008. Archived from the original on 16 August 2008. Retrieved 25 August 2008.  Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; name "us" defined multiple times with different content