Asiru Olatunde
Asiru Olatunde |
---|
Asiru Olatunde (1918–1993) jẹ́ ayàwòrán, alágbẹ̀dẹ ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó jé ọkan lára àwọn gbajúgbajà ayàwòrán ní ìlú Òṣogbo.[1] Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ayàwòrán kékeré kan tí wọ́n darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ àwọn oníṣẹ́-ọnà kan, ìyẹn Oshogbo School of art.[2] Àwọn àwòrán rẹ̀ dá lórí àwọn ìtàn ìgbaani ti ilẹ̀ Yorùbá àti àwọn ìtàn inú Bíbélì.
Ìgbésíayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Asiru Olatunde sínú ìdílé àwọn alágbẹ̀de àmọ́ àìsàn[3] fi ipá gba iṣé yìí ní ọwọ́ rẹ̀ ní ọdún 1960. Ó ṣe àwọn ohun ọ̀ṣọ́ fún títà fún ìgbà díẹ̀ kí ó tó yí iṣẹ́rẹ̀ sí ìyàwòrán, gẹ́gẹ́ bí i àmọ̀ràn tí Uilli Beier àti Suzanne Wenger fun ní ọdún 1961. Ó máa ń fi bàbà, alumíníọ́ọ̀mù àti irin ṣe iṣé rẹ̀,[4] ó sì máa ń fi irin rọ àwọn ẹranko lóríṣiríṣi. Wọ́n ṣàfihàn iṣé rẹ̀ ní IMF headquarters, àti ní Smithsonian Institution bákan náà.[5]
Ikú rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó kú ní ọdún 1993.
Àṣàyàn iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Tree of Life[6]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Ikpakronyi unveils Post COVID-19 vision for NGA, artists". Guardian. Archived from the original on 2024-01-25. Retrieved 2024-01-25.
- ↑ "Asiru Olatunde". Archived from the original on 2007-06-10. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Asiru Olatunde | Indigo Arts". indigoarts.com. Retrieved 2020-10-01.
- ↑ "ASIRU OLATUNDE". Retrieved 2020-09-09.
- ↑ "Asiru Olatunde". Art Network. Retrieved 2020-09-09.
- ↑ "Nairobi Gallery exhibition celebrates 50 years Nigerian art". 2018-04-23. Retrieved 2020-09-09.