Ayọ Tometi
Ìrísí
Ayọ Tometi | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 15 Oṣù Kẹjọ 1984[1] |
Orílẹ̀-èdè | American |
Ẹ̀kọ́ | University of Arizona (BA) Arizona State University (MA) |
Iṣẹ́ | Activist, writer |
Gbajúmọ̀ fún | Black Lives Matter, Black Alliance for Just Immigration |
Website | opaltometi.org |
Ayọ Tometi (tí wọ́n bí ní August 15, 1984), tó fìgbà kan jẹ́ Opal Tometi, jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America. Ó jẹ́ ajàfẹ́tọ̀ọ́-ọmọnìyàn, òǹkọlwé, àti olùṣètò ìlú.[2] Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùṣèdásílẹ̀ Black Lives Matter (BLM).[3] Ó sì fìgbà kan jẹ́ olùdarí àgbà Black Alliance for Just Immigration (BAJI), níbi tó ti ṣiṣẹ́ fún oṣù mẹ́sàn-án.[4]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Williams, Lauren N. (August 29, 2016). "An Influencer from the African Diaspora Who Started an American Movement". Time. Archived from the original on February 20, 2019. https://web.archive.org/web/20190220145516/http://time.com/4463742/opal-tometi-american-voices/. Retrieved February 8, 2019.
- ↑ AYỌ - Opal Tometi BLM Co-Founder Special Announcement (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), archived from the original on November 5, 2021, retrieved November 5, 2021 Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Dalton, Deron (May 4, 2015). "The Three Women Behind the Black Lives Matter Movement". Madame Noire. Archived from the original on December 10, 2018. Retrieved October 15, 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Bhagwat, V. M.; Ramachandran, B. V. (September 15, 1975). "Malathion A and B esterases of mouse liver-I". Biochemical Pharmacology 24 (18): 1713–1717. doi:10.1016/0006-2952(75)90011-8. ISSN 0006-2952. PMID 14. https://pubmed.ncbi.nlm.nih.gov/14. Retrieved November 5, 2021.