Ayodeji Osowobi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Oluwaseun Ayodeji Osowobi
Ọjọ́ìbíLagos
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́Ahmadu Bello University
OrganizationStand to End Rape

Oluwaseun Ayodeji Osowobi jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà tí ó ń já fún ètò àwọn ọmọbìnrin. Ó je Olùdásílẹ̀ STAND TO END RAPE (STER). Ní ọdún 2019, ọ jé ẹnìkejì lóbìnrin tí orúkọ rẹlẹ̀ jẹyọ nínú Time 100 Next, àti nínú Commonwealth Young Person of the Year ní ọdún 2019.

Ìbẹ̀rẹpẹ̀pẹ̀̀́ Ayé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Orúkọ rẹ ní Olúwaṣeun Ayodeji Osowobi, jẹ́ ọmọ bíbí orílé èdè Nàìjíríà, pẹlú àtìlẹ́yìn ìyaarẹ̀ ló fí di Alagbawi (Advocate) [1] Ó gba oyè Bachelor's Degree Local Government Development Studies lẹyìn tí o kàwé ní fásitì tí Ahmadu Bello Ahmadu Bello University[1] before enrolling at Swansea University for a Master’s degree ní nternational Relations. Iṣẹ́ thesis rẹ dojúkọ ìmudọ̀gba láàrin obìnrin àti ọkùnrin, àti àwọn ọ̀ràn ìfipàbánilòpò (gender equality and sex crimes) ti àwọn obìnrin àti ọmọdé ń dojúkọ.[2]

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Nígbà tí ó sìn ìjọba (NYSC), Osowobi ṣíṣe lábé ìjọ INEC ni ọdún 2011 fún ìdìbò gbogbogbò. Nígbà náà, òní "àwọn ará ìlú dé páńpẹ́ fún mi, èyí tí wọn mú ọkàn láàrin àwọn ọkùnrin ìlú láti fí ipá mi lòpò" nígbà tí ó láti gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀. Lẹyìn ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ní ọ da Stand ti End Rape (STER) sílẹ̀ ni 2013.[3][4] Ilé iṣé yìí ń gbèrò láti tún ni polongo ní pá ìwà ipá sí àwọn obìnrin (violence against women) àti láti pèsè àtìlẹ́yìn fún tí irú ẹ̀ tí ṣẹlẹ̀ sí.[5] Títí di 2019, Time estimated the organization had reached around 200,000 Nigerians.[6][7]

Osowobi tí gbà àmi ẹ̀ye Genius Grant láti ọwọ́ John D. Àti Catherine T. MacArthur Foundation ni ọdún 2017. [8]

Ní ọdún 2019, orúkọ rẹ̀ jẹyọ nínúTime 100 Next's people tí ọdún náà, ó sí jẹ́ ẹnìkejì lobinrin tí orúkọ rẹ̀ yóò jáde nínú àkójọ náà.[6] She was also named as the Commonwealth Youth Person of the Year for 2019.[9]

Ní ọdún, Osowobi kó àrùn COVID-19 nígbà tí ó lọ sí United Kingdom Capital ní ọjọ́ kẹsan fún Common Wealth Service. Ara rẹ yà lẹyìn tí ó gbà iwosan, ọ sí sọ bí ọ̀rọ̀ tí rí fún àwọn oníròyìn.[10]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 "Oluwaseun Ayodeji Osowobi". womendeliver.org. Retrieved December 27, 2020. 
  2. Donovan, Ben (March 28, 2018). "Swansea student wins prestigious Commonwealth Young Person of the Year award". 2018.swansea.ac.uk. Retrieved December 27, 2020. 
  3. "From Survivor to Advocate! #BellaNaijaWCW Oluwaseun Ayodeji Osowobi wants Everyone to "Stand to End Rape"". bellanaija.com. 14 March 2018. Retrieved 27 December 2020. 
  4. Ijewere, Esther (27 June 2017). "Oluwaseun Ayodeji Osowobi – Rape survivor and founder, Stand To End Rape Initiative". Guardian. https://guardian.ng/guardian-woman/oluwaseun-ayodeji-osowobi-rape-survivor-and-founder-stand-to-end-rape-initiative/. 
  5. Dark, Shayera (November 6, 2018). "Day in the life: Oluwaseun Osowobi, founder, Stand to End Rape (STER) Initiative". theafricareport.com. The Africa Report. Retrieved December 27, 2020. 
  6. 6.0 6.1 "TIME 100 Next 2019: Oluwaseun Ayodeji Osowobi". Time (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-04-23. 
  7. "The next generation of influential Africans". CNN. Retrieved 2020-04-23. 
  8. Ojo, James (13 November 2019). "Njideka Crosby, Oluwaseun Osowobi… two Nigerians make 2019 ‘TIME 100 Next’ list". lifestyle.thecable.ng. Retrieved 27 December 2020. 
  9. "Nigeria’s Osowobi emerges Commonwealth Youth Person of the Year 2019". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-04-23. 
  10. "Nigeria COVID-19 survivor: ‘An experience I don’t wish on anyone’". aljazeera.com. Al Jazeera English. 7 April 2020. Retrieved 27 December 2020. 

Àdàkọ:Authority control