Ayra Starr

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ayra Starr
Ọjọ́ìbíOyinkansola Sarah Aderibigbe
14 Oṣù Kẹfà 2002 (2002-06-14) (ọmọ ọdún 21)
Cotonou, Benin
Orúkọ mírànCelestial Being
Iléẹ̀kọ́ gígaLes Cours Sonou, University
Iṣẹ́Singer • Songwriter
Ìgbà iṣẹ́2018–present
Musical career
Ìbẹ̀rẹ̀Lagos, Nigeria
Irú orin
InstrumentsVocals
LabelsMavin
Associated acts
Websiteayrastarr.com
Ayra Starr performs "Rush" at Shoke Shoke Festival in Kenya, 2023.

Oyinkansola Sarah Aderibigbe (tí wọ́n bí ní 14 June 2002), tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ sì ń jẹ́ Ayra Starr, jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n bí ní orílẹ̀-èdè Benin. Ó jẹ́ olórin tí ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ nípa ṣíṣe àkọtúnkọ àwọn orin olórin lórí ẹ̀rọ-ayélujára, kí ó ṣe àgbéjáde orin tirẹ̀ gan-an gan. Orin rẹ̀ yìí ló pe àkíyèsi Don Jazzy, tó mu wọ ẹgbẹ́ orin tirẹ̀ tó ń jẹ́ Mavin Records.[1]

Àwon ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Don Jazzy activates Ayra Starr". This Day Live. 30 January 2021. Archived from the original on 28 September 2022. Retrieved 6 April 2021.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)