Ayrton Senna
Appearance
Born | São Paulo, Brazil | 21 Oṣù Kẹta 1960
---|---|
Died | 1 May 1994 Bologna, Italy | (ọmọ ọdún 34)
Formula One World Championship career | |
Nationality | Brazilian |
Active years | 1984–1994 |
Teams | Toleman, Lotus, McLaren, Williams |
Races | 162 (161 starts) |
Championships | 3 (1988, 1990, 1991) |
Wins | 41 |
Podiums | 80 |
Career points | 610 (614) |
Pole positions | 65 |
Fastest laps | 19 |
First race | 1984 Brazilian Grand Prix |
First win | 1985 Portuguese Grand Prix |
Last win | 1993 Australian Grand Prix |
Last race | 1994 San Marino Grand Prix |
Ayrton Senna da Silva (pèé [aˈiɾtõ ˈsenɐ da ˈsiwvɐ] ( listen); Ọjọ́ ọ̀kànlélógún Oṣùkẹta Ọdún 1960 - Ọjọ́ kínín Oṣù karún Ọdún 1994) jẹ́ eléré ìdárayá awakọ̀ ọmọ orílẹ̀ èdè Brazil[1][2] tí ó gba Formula One lẹ́ẹ̀mẹta ní world championships. Ó kú nígbà tí ó ń ṣíwájú nínú ìdíje 1994 San Marino Grand Prix. Ikú rẹ̀ ni ó kẹ́yìn nínụ ìdíje fún Formula One.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |