Bachir Gemayel

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Bachir Pierre Gemayel
Ààrẹ tí wọ́n dìbò yàn
In office
August 23, 1982
AsíwájúElias Sarkis
Arọ́pòAmine Gemayel
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1947-11-10)Oṣù Kọkànlá 10, 1947
Achrafieh, Beirut
AláìsíSeptember 14, 1982(1982-09-14) (ọmọ ọdún 34)
Achrafieh, Beirut
Ẹgbẹ́ olóṣèlúLebanese Forces
(Àwọn) olólùfẹ́Solange Totonji

Bachir Gemayel (Ọjọ́ kẹwá Oṣù kọkànlá ọdún 1947 – Ọjọ́ kẹrìnlá Oṣù kẹsán ọdún 1982) (ó ṣeé kọ bákanáà bí Bashir bẹ́ẹ̀ sì ni orúkọ ìdílé náà ṣeé kọ bí al-Jumayyil, El Gemaiel, Joomayyeel) (بشير الجميّل) jẹ́ olóṣèlú, ọ̀gágun àti ààrẹ orílẹ̀ èdè Lebanese.[1][2] [3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]