Bakitéríà
Baktéríà Temporal range: Archean or earlier - Recent
| |
---|---|
Scanning electron micrograph of Escherichia coli bacilli | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì | |
Àjákálẹ̀: | Bacteria
|
Phyla[1] | |
Actinobacteria (high-G+C)
Aquificae
Acidobacteria |
Baktéríà ( [bækˈtɪərɪə] (ìrànwọ́·info); ìkan: Bakterio) je idipo ninla awon ohun elemintintinni prokarioti ti won ni ahamo eyokan. Gigun won je mitatintinni, idasi bakteria je orisirisi, lati roboto de opa de ilo. Bakteria wa nibi gbogbo ni ile-aye, won wu ninu erupe, omi kikan gbigbona, idoti[2],omi, ati jinjin ninu ile aye, bakanna ninu elo elemin, ati ninu ara awon ogbin ati eranko. 40 legbegberun ahamo bakteria ninu erupe gramu kan be sini egbegberun kan ahamo bakteria lo wa ninu omi; lapapo egbegberunkesan marun (5×1030) bakteria lowa ni aye[3] ti won sedajo opo isupoalaaye ni agbaye.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Bacteria (eubacteria)". Taxonomy Browser. NCBI. Retrieved 2008-09-10.
- ↑ Fredrickson JK, Zachara JM, Balkwill DL, et al. (July 2004). "Geomicrobiology of high-level nuclear waste-contaminated vadose sediments at the Hanford site, Washington state". Applied and Environmental Microbiology 70 (7): 4230–41. doi:10.1128/AEM.70.7.4230-4241.2004. PMC 444790. PMID 15240306. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=444790.
- ↑ Whitman WB, Coleman DC, Wiebe WJ (June 1998). "Prokaryotes: the unseen majority". Proceedings of the National Academy of Sciences of the United States of America 95 (12): 6578–83. doi:10.1073/pnas.95.12.6578. PMC 33863. PMID 9618454. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=33863.