Bambu Shinkafa
Ìrísí
Dambu jẹ́ oúnjẹ àwọn Hausa èyí tí a ṣe láti ara àgbàdo èyí tí a mọ̀ sí tsaki tàbí ìrẹ̀sì, ewé moringa àti kárọ́ọ̀tì (carrot).[1] Onírúurú ẹ̀yà dambu ni a ní, ṣùgbọ́n èyí tí ó gbajúmọ̀ jù ni dambu shinkafa; èyí ni dambu tí wọ́n ṣe láti ara ìrẹsì.[2][3]
Bí a ṣe ń sè é
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A máa se ìrẹ̀sì títí tí ó fi máa rọ̀ dáadáa. Lẹ́yìn ìṣẹ́jú díẹ̀ ni a máa da ewé mọ̀ríngà àti kárọ̀ọ́tì mọ tí a sì ma da ata líló mọ́ ọn, lẹ́yìn náà ni a máa dè é mọ́ orí iná fún ìṣẹ́jú márùndínláàdọ́ta. Lẹ́yìn èyí ni a máa da òróró díndín sí í tí a sì ma jẹ ẹ́.[4]
Àwọn ẹ̀yà mìíràn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Dambun masara, dambun gero etc. are the other types of dambu made by the Hausa.[5]
Wò pẹ̀lú
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Pate is a traditional porridge type of food that is eaten". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-02-17. Archived from the original on 2022-05-31. Retrieved 2022-06-17. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Easy Dambun Shinkafa Recipe (Steamed Rice CousCous) ~ Dee's Mealz". www.deesmealz.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-06-21. Archived from the original on 2022-06-17. Retrieved 2022-06-17. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Dambun Shinkafa, a delicious healthy rice dish from Northern Nigeria -". businessday.ng. Archived from the original on 2022-06-17. Retrieved 2022-06-17. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Dambun shinkafa Recipe by MUHAMMED AISHA". Cookpad (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-06-17. Retrieved 2022-06-17. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Recipe of Favorite Dambun shinkafa - cookandrecipe.com". cookandrecipe.com. Archived from the original on 2022-06-17. Retrieved 2022-06-17. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)