Barbara Jordan (tennis)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Barbara Jordan (ojoibi April 2, 1957, Milwaukee, Wisconsin, U.S.) je obinrin agba tennis to ti feyinti lati orile-ede Amerika to gba Grand Slam obinrin enikan leekan pere ni Open Australia 1979.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]