Jump to content

Naomi Osaka

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Láàrin orúkọ ará Japan yìí, orúkọ ìdílé ni Osaka.
Naomi Osaka
Orílẹ̀-èdè Japan
IbùgbéBoca Raton, Florida, United States
Ọjọ́ìbí16 Oṣù Kẹ̀wá 1997 (1997-10-16) (ọmọ ọdún 26)
Chūō-ku, Osaka, Japan
Ìga1.80 m (5 ft 11 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fàSeptember 2013
Ọwọ́ ìgbáyòRight-handed (two-handed backhand)
Olùkọ́niJermaine Jenkins
Ẹ̀bùn owó$10,733,311
Ojúewé Íntánẹ́ẹ̀tìnaomiosaka.com
Ẹnìkan
Iye ìdíje178–119 (59.93%)
Iye ife-ẹ̀yẹ5 WTA, 0 ITF[1]
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 1 (January 28, 2019)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́No. 2 (March 8, 2021)
Grand Slam Singles results
Open AustrálíàW (2019, 2021)
Open Fránsì3R (2016, 2018)
Wimbledon3R (2017, 2018)
Open Amẹ́ríkàW (2018, 2020)
Àwọn ìdíje míràn
Ìdíje WTARR (2018)
Ẹniméjì
Iye ìdíje2–14 (12.5%)
Iye ife-ẹ̀yẹ0
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 324 (April 3, 2017)
Grand Slam Doubles results
Open Austrálíà1R (2017)
Open Fránsì2R (2016)
Wimbledon1R (2017)
Open Amẹ́ríkà1R (2016)
Àwọn Ìdíje Ẹgbẹ́ Agbáyò
Fed CupWG II PO (2018)
Hopman CupRR (2018)
Last updated on: November 3, 2018.

Naomi Osaka (大坂なおみ Ōsaka Naomi?, born 16 October 1997) jẹ́ agbá bọ́ọ̀ ẹlẹ́yin orí ọ̀dàn fún ilẹ̀ Olómìnira Japan. Òun ni agbá bọ́ọ̀lù ẹlẹ́yin orí ọ̀dàn ará Japan àkọ́kọ́ tó gba Ife-ẹ̀yẹ ìdíje Grand Slam, nígbà tí ó borí alátakò rẹ̀ Serena Williams nínú àṣekágbá ìdíje Open Amerika 2018 ti ọdún 2018.[2] Osaka ti dé ipò 1k láglagbaye tó sì jẹ́ ipò rẹ̀ tó ga jọ ní ọjọ́ Kejìdínlọ́gbọn oṣù Kínní ọdún 2019 ( 28, 2019).[3]


Àwọn Ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named itf-profile
  2. Rothenberg, Ben. "U.S. Open Tennis Final: Naomi Osaka Defeats Serena Williams" (in en). https://www.nytimes.com/2018/09/08/sports/serena-williams-vs-naomi-osaka-us-open.html. 
  3. "Naomi Osaka" (in en). WTA Tennis. 2018-07-16. http://www.wtatennis.com/players/player/319998/title/naomi-osaka-0.