Dinara Safina

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Dinara Safina
Динара Сафина
Safina Roland Garros 2009 1.jpg
Orílẹ̀-èdè Rọ́síà Rọ́síà
Ibùgbé Monte Carlo, Monaco
Ọjọ́ìbí Oṣù Kẹrin 27, 1986 (1986-04-27) (ọmọ ọdún 33)
Moscow, Soviet Union
Ìga 1.82 m (5 ft 11+12 in)[1]
Ìgbà tódi oníwọ̀fà 2000
Ọwọ́ ìgbáyò Right-handed (two-handed backhand)
Ẹ̀bùn owó US10,585,640
Ẹnìkan
Iye ìdíje 360–173 (67.54%)
Iye ife-ẹ̀yẹ 12 WTA, 4 ITF
Ipò rẹ̀ gígajùlọ No. 1 (April 20, 2009)
Grand Slam Singles results
Open Austrálíà F (2009)
Open Fránsì F (2008, 2009)
Wimbledon SF (2009)
Open Amẹ́ríkà SF (2008)
Àwọn ìdíje míràn
Ìdíje WTA RR (2008, 2009)
Ìdíje Òlímpíkì Silver medal.svg Silver medal (2008)
Ẹniméjì
Iye ìdíje 181–91
Iye ife-ẹ̀yẹ 9 WTA, 3 ITF
Ipò rẹ̀ gígajùlọ No. 8 (May 12, 2008)
Grand Slam Doubles results
Open Austrálíà QF (2004, 2005)
Open Fránsì 3R (2006, 2007, 2008)
Wimbledon 3R (2005, 2008)
Open Amẹ́ríkà W (2007)
Àwọn ìdíje Ẹniméjì míràn
Ìdíje Òlímpíkì QF (2008)
Last updated on: October 10, 2011.

Dinara Mikhailovna Safina (Rọ́síà: Динара Михайловна Сафина, Àdàkọ:Lang-tt), ojoibi April 27, 1986 ni Moscow, je agba tenis ara Rosia lati eya Tatari. Safina de ifunnipo No. 1 Lagbaye bi enikan.

Safina gba ipo keji ninu awon idije Grand Slam enikan ni 2008 French Open, 2009 Australian Open, ati 2009 French Open, nibi to ti kuna lowo Ana Ivanovic, Serena Williams, ati Svetlana Kuznetsova, ni telentele.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named WTA_Stats