Bianca Andreescu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Bianca Andreescu
Andreescu in 2015
Orílẹ̀-èdè Canada
IbùgbéThornhill, Ontario, Canada[1]
Ọjọ́ìbí16 Oṣù Kẹfà 2000 (2000-06-16) (ọmọ ọdún 23)
Mississauga, Ontario, Canada
Ìga1.70 m
Ìgbà tódi oníwọ̀fà2017
Ọwọ́ ìgbáyòRight-handed (two-handed backhand)
Olùkọ́niSylvain Bruneau
Ẹ̀bùn owóUS$6,720,038
Ẹnìkan
Iye ìdíje137–50 (73.26%)
Iye ife-ẹ̀yẹ3
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 4 (28 October 2019)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́No. 6 (9 March 2020)
Grand Slam Singles results
Open Austrálíà2R (2019)
Open Fránsì2R (2019)
Wimbledon1R (2017)
Open Amẹ́ríkàW (2019)
Àwọn ìdíje míràn
Ìdíje WTARR (2019)
Ẹniméjì
Iye ìdíje29–16 (64.44%)
Iye ife-ẹ̀yẹ0
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 147 (16 July 2018)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́No. 1214 (3 February 2020)
Grand Slam Doubles results
Open Amẹ́ríkà1R (2019)
Àwọn Ìdíje Ẹgbẹ́ Agbáyò
Fed CupPO (2019)
Last updated on: 3 February 2020.

Bianca Vanessa Andreescu (Àdàkọ:IPA-ro; ọjọ́ìbí June 16, 2000) ni agbá tẹ́nìs ará Kánádà. Ipò rẹ̀ lágbààyé tó gajùlọ ni No. 4, òhun ni ará Kánádà tí ipò rẹ̀ gajùlọ láti ìbẹ̀rẹ̀ àjọ Women's Tennis Association (WTA). Andreescu gba ife-ẹ̀yẹ Open Amẹ́ríkà 2019 àti ife-ẹ̀yẹ Open Kánádà 2019 nígbà tó borí Serena Williams ní ìparí ìdíje mẹ́jẹ́èjì.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Bianca Andreescu". WTA Tennis. Retrieved September 6, 2019.