Bàrbúdà
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Barbuda)
Jẹ́ọ́gráfì | |
---|---|
Ibùdó | Caribbean Sea |
Àwọn ojú-afọ̀nàhàn | 17°37′N 61°48′W / 17.617°N 61.800°WCoordinates: 17°37′N 61°48′W / 17.617°N 61.800°W |
Àgbájọ erékùṣù | Leeward Islands, Lesser Antilles |
Ààlà | 160.56 km2 (61.993 sq mi) |
Ibí tógajùlọ | 38 m (125 ft) |
Orí ilẹ̀ tógajùlọ̀ | Highlands |
Orílẹ̀-èdè | |
Antigua and Barbuda | |
Ìlú tótóbijùlọ | Codrington (pop. 1,252) |
Demographics | |
Ìkún | 1,370 |
Ìsúnmọ́ra ìkún | 9.34 /km2 (24.19 /sq mi) |
Barbuda je erekusu ni Apailaorun Karibeani, o si je apa orile-ede Antigua ati Barbuda. O ni olugbe to to bi 1,500, opo won ti won ungbe ni ilu Codrington.
Barbuda budo si ariwa Antigua, larin awon Erekusu Leeward. Ni guusu re ni awon erekusu Montserrat ati Guadaloupe wa, ati ni ariwa ati iwoorun re ni Nevis, St. Kitts, St. Barts, ati St. Martin wa.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |