Benedict Akwuegbu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Benedict Akwuegbu
Personal information
OrúkọBenedict Akwuegbu
Ọjọ́ ìbí3 Oṣù Kọkànlá 1974 (1974-11-03) (ọmọ ọdún 49)
Ibi ọjọ́ibíJos, Nigeria
Ìga1.80 m (5 ft 11 in)
Playing positionStriker
Youth career
1989–1991Mighty Jets F.C.
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
1991–1992RC Lens
1992–1993K.S.C. Eendracht Aalst15(3)
1994–1996Harelbeke49(14)
1996–1997Waregem16(9)
1997–1998Tienen27(4)
1998–2002Grazer AK100(31)
2002Shenyang Ginde (loan)18(2)
2002–2004Grazer AK20(7)
2004FC Kärnten14(6)
2004–2005St. Gallen12(3)
2005–2006Wacker Innsbruck11(0)
2006Siegen10(1)
2006Tianjin Teda (loan)6(3)
2006–2007Panserraikos10(12)
2007Qingdao Jonoon20(6)
2008Beijing Hongdeng7(2)
2009–2010Basingstoke Town4(1)
National team
2000–2005Nigeria35(10)
Teams managed
2012–2013Heartland F.C. (Asst General Manager)
2015–2016FC Gratkorn (Manager)
2016–Mighty Jets F.C. (Technical Director)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Benedict Akwuegbu (tí a bí ní ọjọ́ kẹta oṣù kọkànlá ọdún 1974) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ẹlẹ́sẹ̀ ti tẹ́lẹ̀ tó fẹ̀hìntì.

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Iṣẹ́ Agbábọ́ọ̀lù Rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Early career[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Akwuegbu bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ agbábọ́ọ̀lù ẹlẹ́sẹ̀ rẹ̀ nígbà tí ó wà ní àárun-dín-lógún ọdún ní ọjọ́ orí ní Nàìjíríà kí ó tó lọ sí French outfit RC Lens nígbà tí ó wà ní ẹ̀ẹ́ta-dín-lógún ọdún ní ọjọ́ orí. [1] Lẹ́hìn náà, ó lo ọdún márùn-ún ní Belgium pẹ̀lú KRC Harelbeke, KSV Waregem, KVK Tienen. Ẹgbẹ́ Austrian Grazer AK ṣe ìtẹ́wọ́gbà rẹ̀ lẹ́hìn àsìkò odún 1998.

Ìyìn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Grazer AK
International

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Benedict Akwuegbu". National-Football-Teams.com. Retrieved 17 June 2008.