Jump to content

Benjamin Kalu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

    Benjamin Kalu
    Deputy Speaker of the House of Representatives of Nigeria
    Lọ́wọ́lọ́wọ́
    Ó gun orí àga
    13 June 2023
    SpeakerTajudeen Abbas
    AsíwájúAhmed Idris Wase
    Member of the
    House of Representatives of Nigeria
    from Abia
    Lọ́wọ́lọ́wọ́
    Ó gun orí àga
    11 June 2019
    ConstituencyBende
    Àwọn àlàyé onítòhún
    Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
    Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressives Congress
    Other political
    affiliations
    Peoples Democratic Party
    Progressive Peoples Alliance
    ResidenceAbuja, Nigeria
    OccupationPolitician

    Benjamin Okezie Kalu jẹ́ gbajúgbajà olóṣèlú omo orílẹ̀-èdè Nàíjírìa , tó ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi igbákejì olórí ilé ìgbimọ̀ aṣòfin àgbà orílẹ̀ èdè Naìjíríà láti ọdún 2023 [1]. Ìdìbò rẹ sí ipò yìí ní awon akegbe re nile igbimo asofin abga fowosi. Kalu n ṣe aṣojú fun agbègbè àpapò Bende, tí ó si mu ero ati ohun ti awon eniyanre fe wa si ile asofin agba ni orílẹ̀-èdè Naijiiria. [2]

    Ìgbésí ayé, ẹ̀kọ́ àti iṣẹ́ ìṣèlú

    [àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

    Ojó karùn-ún osù karùn-ún odún 1971 ni wọ́n bí Benjamin Okezie Kalu ní Agbamuzu, ní ìjoba ìbílẹ̀ Bende ní ìpínlẹ̀ Abia. Ó ṣe aṣojú agbègbè Bende Federal Constituency àti pé ó ti pinnu láti ṣe ìdásí sí ìdàgbàsókè orílẹ̀-èdè nípasẹ̀ àwọn ìlànà ìṣòfin, ìmúse iṣẹ́ àkànṣe, àti ìdàgbàsókè ènìyàn. Gẹ́gẹ́ bí aṣòfin àti agbẹnusọ fún Àpéjọ kẹsàn-án ti Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣojú ní Nàìjíríà, ó ti gba ìyìn àgbáyé fún àwọn ìgbìyànjú rẹ̀ nínú ìdàgbàsókè orílẹ̀-èdè àti àwọn ìlànà ṣíṣe òfin.

    Àwọn ìtọ́kasí

    [àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
    1. Mojeed, Abdulkareem (2023-06-13). "Benjamin Kalu emerges Deputy Speaker House of Reps". Premium Times Nigeria. Retrieved 2023-11-24.
    2. "10th NASS: Benjamin Kalu sworn in as Deputy Speaker". Vanguard News. https://www.vanguardngr.com/2023/06/10th-nass-benjamin-kalu-sworn-in-as-deputy-speaker/.