Bẹ̀rmúdà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Bermuda)
Jump to navigation Jump to search
Bẹ̀rmúdà
Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
Motto"Quo Fata Ferunt"  (Latin)
"Whither the Fates Carry [Us]"
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdè"God Save the Queen" (official)
"Hail to Bermuda" (unofficial)
OlúìlúHamilton
32°18′N 64°47′W / 32.3°N 64.783°W / 32.3; -64.783
Ìbílẹ̀
St. George's
Èdè àlòṣiṣẹ́ Gẹ̀ẹ́sì1
Èdè míràn Portuguese1
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn  54.8% African-Caribbean
34.1% white
6.4% multiracial
4.3% other
0.4% unspecified[1]
Orúkọ aráàlú Ará Bermuda
Ìjọba Àwọn ilẹ̀ òkèrè Brítánì
 -  Adobaje Queen Elizabeth II
 -  Gomina Sir Richard Gozney
 -  Asiwaju Paula Cox
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 53.2 km2 (224th)
20.6 sq mi 
 -  Omi (%) 26%
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2009 67,837[1] (199th)
 -  2000 census 62,059 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 1,275/km2 (7th)
3,293/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2007[2]
 -  Iye lápapọ̀ $5.85 billion[2] (149th)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $91,477[2] (1st)
HDI (2003) n/a (n/a) (n/a)
Owóníná Bermudian dollar2 (BMD)
Àkókò ilẹ̀àmùrè Atlantic (UTC-4)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ osi
Àmìọ̀rọ̀ Internet .bm
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù +1-441
1 According to CIA World Factbook.
2 On par with US$.

Bermuda (pípè /bɜrˈmjuːdə/; lonibise bi, àwọn Bẹ̀rmúdà tabi Àwọn Erékùṣù Somers) je ile-agbegbe okere Britani ni Ariwa Okun Atlantiki. O budo si ilaorun etiokun awon Ipinle Aparapo, isupoile to sunmo julo ni Cape Hatteras, North Carolina, bi 1,030 kilometres (640 mi) si iwoorun-ariwaiwoorun. O wa bi 1,373 kilometres (853 mi) guusu Halifax, Nova Scotia, Kanada, ati 1,770 kilometres (1,100 mi) ariwailaorun Miami, Florida. Oluilu re ni Hamilton sugbon ibile titobijulo ni ilu Saint George's.

Bermuda ni ile-agbegbe okere Britani toseku topejulo to si ni olugbe julo, o je bibudo si latowo Ilegeesi ni ogorun odun ki ofin Isoka 1707 to da Ileoba Britani Olokiki aparapo sile. Oluilu Bermuda akoko, St George's, je bibudo sori ni 1612 o si je ilu Ilegeesi ni Amerika topejulo ti awon eniyan ungbe nibe.[3]

Okowo Bermuda dara daada, pelu inawo bi eka okowo re totobijulo, leyin re ni isebewo,[3][4] awon wonyi fun ni GIO tenikookan to gajulo lagbaye ni 2005. O ni ojuojoabeonileoloru .[5]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 Central Intelligence Agency (2009). "Bermuda". The World Factbook. Retrieved 23 January 2010. 
  2. 2.0 2.1 2.2 Bermuda leads in GDP per capita, The Royal Gazette, 07/12/08
  3. 3.0 3.1 "Bermuda - History and Heritage". Smithsonian.com. 6 November 2007. Retrieved 3 December 2008. 
  4. “Bermuda's Tourism Industry” Tayfun King, Fast Track, BBC World News (3 Nov. 2009)
  5. Forbes, Keith. "Bermuda Climate and Weather". The Royal Gazette. Retrieved 28 Oct. 2008.  Check date values in: |access-date= (help)