Bernice Carr Vukovich

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Bernice Carr Vukovich
Orílẹ̀-èdèGúúsù Áfríkà South Africa
Ọjọ́ìbí12 Oṣù Kínní 1938 (1938-01-12) (ọmọ ọdún 86)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà1954
Ìgbà tó fẹ̀yìntì1969
Ẹnìkan
Iye ife-ẹ̀yẹ17 ITF
Grand Slam Singles results
Open Austrálíà1R (1965)
Open Fránsì3R (1958)
Wimbledon4R (1958)
Open Amẹ́ríkàQF (1960)
Ẹniméjì
Iye ife-ẹ̀yẹ5 ITF
Grand Slam Doubles results
Open Austrálíà2R (1965)
Open FránsìQF (1958)
Wimbledon3R (1962)
Grand Slam Mixed Doubles results
Open Fránsì2R (1960)
Wimbledon4R (1960)

Bernice Carr Vukovich (tí wọ́n bí ní 12 January 1938) jẹ́ afẹ̀yìntì agbábọ́ọ̀lù orí tábìlì láti ìlú South Africa, àmọ́ tí orísun rẹ̀ jẹ́ ìlú Croatia. Bàbá rẹ̀ ṣí lọ sí ìlú Croatia láti peninsula ti Pelješac.[1]

Bernice parí ẹ̀kọ́ girama rẹ̀ ní End Street Convent (Holy Family order), tó sì kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní ọdún 1955. Ó jẹ́ ajáwé olúborí fún South African junior tennis champion ní ọdún 1954 àti 1955.[1] Nígbà tó bẹ̀rẹ̀ sí ní kópa nínú ìdíje àwọn àgbà, ó yege ní South African championship tí ọdún 1958 àti 1959,[1] ní ti ọdún 1959, ó gbé ipò kejì. Ní ọdún 1958, ó yege nínú ìdíje pẹ̀lú Heather Brewer-Segal pẹ̀lú ayò 3–6, 7–5, 6–4. Ní ọdún 1959, ó pàdánù oyè náà nínú ìdíje pẹ̀lú Sandra Reynolds, pẹ̀lú ayò 6–0, 8–6. Ní ọdún 1960, ó tún yege, tó sì gba oyè náà padà nígbà tí ó na Sandra Reynolds pẹ̀lú ayò 6–1, 2–6, 12–10.

Ní ọdún 1965 Bernice Vukovich na Luisa Bassi (Italy) 7–5,6–0 láti fi jawé olúborí nínú ìdíje gbogboogbò tó wáyé ní Palermo, Sicily.

Ó gbá bọ́ọ̀lù náà fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìdíje ní àgbáyé.[1] Ó kópa nínú ìdíje Federation Cup ti ọdún 1965. Ó fìdí rẹmi nínú ìdíje náà, èyí tó mú kí Christine Janes, yege. Nínú eré mìíràn tó gbá, ó tún fìdí rẹmi bákan náà, èyí tó mú kí Ann Haydon Jones àti Deidre Keller jáwé olúborí.[2]

Èsì ìdíje àṣekágbá ti ITF[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Legend
$10,000 tournaments

Singles (17–8)[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Result No. Date Tournament Surface Opponent Score
Loss 1. 19 May 1956 Paddington, United Kingdom Hard Gúúsù Áfríkà Sandra Reynolds 6–3, 0–6, 4–6
Win 2. 17 November 1956 Benoni, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Estelle van Tonder 6–2, 6–3
Loss 3. 1 December 1956 East London, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Beryl Bartlett 8–10, 6–1, 1–6
Loss 4. 1 January 1957 Port Elizabeth, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Heather Brewer-Segal 2–6, 2–6
Loss 5. 12 January 1957 Cape Town, South Africa Hard Austrálíà Daphne Seeney 3–6, 5–7
Win 6. 7 October 1957 Johannesburg, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Jean Forbes 3–6, 6–3, 6–2
Loss 7. 12 January 1958 East London, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Gwendy Love 4–6, 6–4, 4–6
Win 8. 4 April 1958 Johannesburg, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Heather Brewer-Segal 3–6, 7–5, 6–4
Win 9. 21 June 1958 London, United Kingdom Grass Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Margaret Varner Bloss 6–4, 5–7, 8–6
Win 10. 20 September 1958 Johannesburg, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Estelle van Tonder 6–3, 6–1
Win 11. 3 January 1959 East London, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Dora Kilian 2–6, 6–3, 6–4
Win 12. 1 March 1959 Bloemfontein, South Africa Clay Gúúsù Áfríkà Estelle van Tonder 6–1, 6–2
Loss 13. 29 March 1959 Johannesburg, South Africa Clay Gúúsù Áfríkà Sandra Reynolds 0–6, 6–8
Win 14. 26 July 1959 Pietermaritzburg, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Dora Kilian 6–3 6–8 6–1
Win 15. 19 September 1959 Johannesburg, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Joan Cross 6–3, 6–1
Win 16. 2 January 1960 East London, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Valerie Forbes 6–3 6–3
Loss 17. 9 January 1960 Cape Town, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Sandra Reynolds 4–6, 4–6
Win 18. 18 April 1960 Johannesburg, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Sandra Reynolds 6–1 2–6 12–10
Win 19. 1 May 1960 Palermo, Italy Clay Austrálíà Jan Lehane 6–4, 6–3
Win 20. 3 July 1960 Berlin, West Germany Clay Ìwọ̀orùn Jẹ́mánì Edda Buding 12–10, 6–4
Loss 21. 16 July 1960 Newport, Wales, United Kingdom Grass United Kingdom Angela Mortimer 9–11, 3–6
Win 22. 31 July 1960 Hilversum, Netherlands Clay Gúúsù Áfríkà Renée Schuurman 6–0, 6–1
Win 23. 26 December 1960 East London, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Valerie Forbes 6–3, 6–3
Win 24. 5 September 1964 Johannesburg, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Heather Brewer-Segal 7–5, 9–7
Win 25. 19 April 1965 Johannesburg, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Jean Forbes 6–4, 7–5

Doubles (5–15)[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Outcome No. Date Tournament Surface Partner Opponents Score
Loss 1. 7 January 1955 Port Elizabeth, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Lucille van der Westhuizen Gúúsù Áfríkà Dora Kilian
Gúúsù Áfríkà Leonie Vermaak
1–6, 1–6
Win 2. 14 July 1956 Sunderland, United Kingdom Grass Gúúsù Áfríkà Merrill Hammill United Kingdom Rosemary Bulleid
United Kingdom Georgie Woodgate
W/O
Loss 3. 17 November 1956 Benoni, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Merrill Hammill Gúúsù Áfríkà Lynette Hutchings
Nẹ́dálándì Yvonne van der Linde
2–6, 6–3, 2–6
Loss 4. 12 January 1957 Cape Town, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Merrill Hammill Austrálíà Daphne Seeney
Gúúsù Áfríkà Valerie Forbes
8–10, 0–6
Loss 5. 7 October 1957 Johannesburg, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Estelle Van Tonder Gúúsù Áfríkà Beryl Bartlett
Gúúsù Áfríkà Joan Scott
2–6, 0–6
Loss 6. 14 June 1958 Beckenham, United Kingdom Grass Gúúsù Áfríkà Jean Forbes New Zealand Sonia Cox
New Zealand Ruia Morrison
1–6, 3–6
Loss 7. 20 September 1958 Johannesburg, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Estelle van Tonder Gúúsù Áfríkà Beryl Bartlett
Gúúsù Áfríkà Joan Scott
2–6, 3–6
Loss 8. 3 January 1959 East London, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Estelle van Tonder Gúúsù Áfríkà Beryl Bartlett
Gúúsù Áfríkà Dora Kilian
0–6, 0–6
Loss 9. 2 January 1960 East London, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Peggy Pentelow Gúúsù Áfríkà Jean Forbes
Gúúsù Áfríkà Valerie Forbes
3–6 4–6
Loss 10. 9 January 1960 Cape Town, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Heather Brewer-Segal Gúúsù Áfríkà Sandra Reynolds
Gúúsù Áfríkà Renee Schuurman
5–7, 1–6
Loss 11. 18 April 1960 Johannesburg, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Heather Brewer-Segal Gúúsù Áfríkà Sandra Reynolds
Gúúsù Áfríkà Renee Schuurman
11–13, 9–7, 1–6
Win 12. 4 June 1960 Birmingham, United Kingdom Grass Brasil Maria Bueno United Kingdom Ann Jones
United Kingdom Angela Mortimer
6–3, 7–5
Loss 13. 11 June 1960 Bristol, United Kingdom Grass Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Gwyn Thomas Gúúsù Áfríkà Sandra Reynolds
Gúúsù Áfríkà Renee Schuurman
5–7, 3–6
Win 14. 16 July 1960 Newport, Wales, United Kingdom Grass United Kingdom Angela Mortimer United Kingdom Rita Bentley
United Kingdom Jill Rook Mills
6–1, 6–1
Loss 15. 31 July 1960 Hilversum, Netherlands Clay Gúúsù Áfríkà Renée Schuurman Gúúsù Áfríkà Margaret Hunt
Gúúsù Áfríkà Lynette Hutchings
6–4, 4–6, 5–7
Loss 16. 16 September 1961 Johannesburg, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Valerie Forbes Gúúsù Áfríkà Annette Van Zyl
Gúúsù Áfríkà Joan Cross
3–6, 3–6
Loss 17. 29 September 1962 Johannesburg, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Estelle van Tonder Gúúsù Áfríkà Beryl Bartlett
Gúúsù Áfríkà Jean Forbes
1–6, 7–5, 4–6
Loss 18. 15 April 1963 Johannesburg, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Marlene Gerson Gúúsù Áfríkà Margaret Hunt
Gúúsù Áfríkà Annette Van Zyl
2–6, 7–9
Win 19. 6 February 1965 Pretoria, South Africa Hard United Kingdom Christine Truman Gúúsù Áfríkà Sandra Reynolds
Gúúsù Áfríkà Heather Brewer-Segal
2–6, 6–1, 6–4
Win 20. 19 April 1965 Johannesburg, South Africa Hard Gúúsù Áfríkà Marlene Gerson Gúúsù Áfríkà Jean Forbes
Gúúsù Áfríkà Valerie Forbes
7–5, 7–5

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 Geni.com Early Croatian Settlers in South Africa]
  2. "South Africa v Great Britain". fedcup.com. Archived from the original on 23 October 2014. https://web.archive.org/web/20141023194219/http://www.fedcup.com/en/results/tie/details.aspx?tieId=20005130.