Betta Edu
Ìrísí
Dr. Betta Edu | |
---|---|
Commissioner for Health Cross River State | |
In office December 2019 – títí di ìsinsìnyí | |
Adarí ẹgbẹ́ àwọn obìnrin All progressives Congress | |
In office March 2022 – títí di ìsinsìnyí | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 27 Oṣù Kẹ̀wá 1986 Ibalebo Abi LGA Ìpínlẹ̀ Rivers, Nàìjíríà |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressives Congress (2021–present) |
Alma mater | Yunifásitì ìlú Calabar |
Occupation | Physician, Public Health Specialist |
Betta C. Edu (tí a bí ní ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gbọ́n oṣù Kẹ̀wá ọdún 1986[1]) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ni kọmíṣọ́nà fún ètò ìlera ara ní Ìpínlẹ̀ Cross River àti alága ẹgbẹ́ àwọn Kọmíṣọ́nà ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedpunchng