Jump to content

Bharrat Jagdeo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Bharrat Jagdeo Junior
8th President of Guyana
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
11 August 1999
Alákóso ÀgbàSam Hinds
AsíwájúJanet Jagan
8th Prime Minister of Guyana
In office
9 August 1999 – 11 August 1999
ÀàrẹJanet Jagan
AsíwájúSam Hinds
Arọ́pòSam Hinds
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí23 Oṣù Kínní 1964 (1964-01-23) (ọmọ ọdún 60)
Unity Village, Guyana
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Progressive Party
(Àwọn) olólùfẹ́Varshni Jagdeo (Divorced)

Bharrat Jagdeo tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù Kíní ọdún 1964 jẹ́ ̀Aàrẹ orílẹ̀-èdè Guyana láti ọjọ́ Kọkànlá oṣù Kẹjọ ọdún 1999. Ó jẹ́ Alákòóso ètò ìṣúná[1] kí ó tó di Ààrẹ lẹ́yìn tí Ààrẹ Janet Jagan kúrò nípò.