Jump to content

Janet Jagan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Janet Rosenberg Jagan
Janet Jagan
7th President of Guyana
In office
19 December 1997 – 11 August 1999
Alákóso ÀgbàSam Hinds
Bharrat Jagdeo
AsíwájúSam Hinds
Arọ́pòBharrat Jagdeo
6th Prime Minister of Guyana
In office
6 March 1997 – 19 December 1997
ÀàrẹSam Hinds
AsíwájúSam Hinds
Arọ́pòSam Hinds
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1920-10-20)20 Oṣù Kẹ̀wá 1920
Chicago, Illinois, USA
Aláìsí28 March 2009(2009-03-28) (ọmọ ọdún 88)
Georgetown, Guyana
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Progressive Party
{{{blank1}}}Cheddi Jagan

Janet Rosenberg Jagan tí wọ́n bí ní Ọjọ́ ogúnjọ́ oṣù kẹwàá ọdún 1920, tí ó sìn kú ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù Kẹta ọdún 2009 (October 20, 1920 - March 28, 2009)[1][2][3] lo jẹ́ olóṣèlú àti Ààrẹ-àná Aare orílẹ̀-èdè Guyana láti ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù Kejìlá 1997 sí ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹta ọdún 1999. Ó sìn di olóògbé lọ́dún 2009.



Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]