Binos Dauda Yaroe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Binos Dauda Yaroe
Sénátọ̀
Lọ́wọ́lọ́wọ́June 11, 2019 títí di ìsinsìnyí
AsíwájúSen. Ahmed Abubakar Mo'Allahyidi
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíJanuary 1, 1955
Ọmọorílẹ̀-èdèNàìjíríà
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party (PDP)
BàbáDauda Yaroe
ProfessionPolitician

Sen. Binos Dauda Yaroe jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Sénátọ̀ tí ó ń sójú agbègbè Adamawa South Senatorial District ti Ìpínlẹ̀ Adamawa[1] ní ilé ìgbìmò Aṣòfin àgbà lọ́wọ́lọ́wọ́.[2][3][4]

Ìpìlẹ̀ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Binos Dauda Yaroe ní ọjọ́ kínní oṣù kínní ọdún 1955, ní Wagole, abúlé kan ní agbègbè Ribadu Ward ti ìjọba ìbílè Mayo-BelwaÌpínlẹ̀ Adámáwá, Nàìjíríà. Ó fẹ́ Mrs. Gimbiya Joshua, ní ọdún 1983; wọ́n bí ọmọ mẹ́rin.[5]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Senate President Ahmed Lawan praises Binos over impact of medical outreach". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-12-09. Retrieved 2022-03-18. 
  2. "PDP Claims Adamawa South Senatorial Seat". aitonline.tv. 
  3. "APC commands Senate majority with 63 Senators, PDP behind with 44". http. March 12, 2019. 
  4. "Inconclusive Polls: Who wins Kano, Sokoto, Bauchi, Adamawa, Benue Plateau?". The Nation Newspaper. March 16, 2019. https://thenationonlineng.net/supplementary-pollswho-wins-kano-sokoto-bauchi-adamawa-benue-plateau/. 
  5. "Nigeria ScoreCard". www.nigeriascorecard.com. Archived from the original on 2021-06-28. Retrieved 2021-06-28.