Jump to content

Blackface

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Blackface Naija
(Blackface)
Orúkọ àbísọAhmedu Augustine Obiabo
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiBlackface
Ọjọ́ìbíOgwule, Agatu, Benue State, Nigeria
Irú orinDancehall, ragga, reggae, hip hop
Occupation(s)Singer, songwriter, record producer
Years active1997–present
Associated acts2face Idibia, Faze, Plantashun Boyz, D Tribunal, Main Eazz

Ahmedu Augustine Obiabo (tí a bí ní Ogwule, ìlú Agatu, ipinle Benue, Naijiria),[1] tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Blackface Naija tàbí Blackface, jẹ́ olórin, oníjó àti akọrin-sílẹ̀. Ó di gbajúmọ̀ nígbà tí ó kọrin "African Queen" pẹ̀lú 2face Idibia ní ọdú 2004.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]