Bode Akindele
Ìrísí
Bode Akindele | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Oyo, Nigeria | Oṣù Kẹfà 2, 1933
Aláìsí | June 29, 2020 Apapa, Lagos State, Nigeria | (ọmọ ọdún 87)
Iṣẹ́ | Olokun-Owo ti o lami laaka, oludari ile ise Madandola Group ati ti Fairgate Properties |
Àwọn ọmọ | Folake Coker & Oladipo Akindele[1] |
Parent(s) |
|
Website | modandolagroups.com |
Oloye Bode Akindele (2 June 1933 - 29 June 2020) jẹ onimọran ile-iṣẹ orilẹ-ede Naijiria kan ati Parakoyi ti ilu Ibadanland, ti apapọ iye oro re to $ 1.19 bilionu, gẹgẹ bi iwadi ti Ventures Africa se ti won si gbe jade ni ọdun 2013 ninu iwe iroyin Daily Telegraph . [2] O je eni ikerindinlogun ti o lowo julo ni orile ede Naijiria gege bi BuzzNigeria ti se apejuwe. Akindele ni oludasile ati Alaga ti Madandola Group, onisowo oju-omi, ile ise ti o n se orisirisi ohun elo, ti olu-ile ise re wa ni United Kingdom.[3]
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Segun. "Billionaire businessman, Chief Bode Akindele is dead". The Express NG. Archived from the original on 2 July 2020. Retrieved 30 June 2020.
- ↑ Burn-Callander. "Africa boasts 55 billionaires from 10 countries" (in en-GB). https://www.telegraph.co.uk/journalists/rebecca-burn-callander/10361675/Africa-boasts-55-billionaires-from-10-countries.html.
- ↑ Oyewale, Wale (2020-06-29). "Renowned businessman, Bode Akindele, is dead". Punch Newspapers. Retrieved 2020-08-09.