Jump to content

Bosede Bukola Afolabi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Bosede Bukola Afolabi
Ọjọ́ìbíLondon, England
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iléẹ̀kọ́ gígaQueen’s College Yaba, Obafemi Awolowo University, University of Nottingham
Iṣẹ́Consultant Obstetrician, Gynaecologist & Professor
Gbajúmọ̀ fúnProfessor of Obstetrics and Gynaecology, Director of the Centre for Clinical Trials, Research and Implementation Science (CCTRIS) at the University of Lagos

Bosede Bukola Afolabi jẹ́ Dókítà ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jẹ́ onímọ̀ nípa àìsàn ojú ara àwọn obìnrin, òjògbón àti adarí ẹ̀ka àwọn olóyún àti àwọn àìsàn ti ojú ara obìnrin ní ilé ìwòsàn ti Yunifásitì Ìpínlẹ̀ Èkó, Èkó, Nàìjíríà.[1] Òun tún ni ọ̀lùdásílẹ̀ àti alága MRH (Maternal and Reproductive Health) Research Collective.[1]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 Vladimir Duthiers,"Nigerian doctor fighting killer blood disease". edition.cnn.com. 3 March 2017. Retrieved 8 December 2021.