Boyland–Sims oxidation
Ìrísí
Boyland–Sims oxidation jẹ́ ìdàpapọ̀ ṣiṣẹ́ kẹ́míkà ti àwọn aniline pẹ̀lú alkaline potassium persulfate, tí ó jẹ́ pé lẹ́yìn dídomi sí rẹ̀ ó maa di ortho-hydroxyl àwọn aniline.[1][2][3]
Ortho-isomer ló maa ń jẹyọ. Síbẹ̀síbẹ̀, para-sulfate maa jẹyọ ní bíntí pẹ̀lú àwọn analine kan .[4]
Ètò ìdàpọ̀ ṣiṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Behrman ti fihàn pé oun àkọ́kọ́ tí a maa rí nínú Boyland–Sims oxidation ni jíjẹyọ arylhydroxylamine-O-sulfate (2).[5] Àtúntò zwitterionic yìí maa jẹ́ kí a rí ortho- sulfate (5), tí a maa domisí lati lè rí ortho-hydroxyl aniline.
Ìwé àkàsíwájú si
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Behrman, Edward J. (2014). "On the Mechanism of the Boyland-Sims Oxidation". Progress in Reaction Kinetics and Mechanism (Science Reviews 2000 Ltd) 39 (3): 308–310. doi:10.3184/146867814X14062204626705. Archived from the original on 2016-07-16. https://web.archive.org/web/20160716153749/http://www.sciencereviews2000.co.uk/view/journal/progress-in-reaction-kinetics-and-mechanism.
Tún wo
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Boyland, E.; Manson, D.; Sims, Peter (1953). "729. The preparation of o-aminophenyl sulphates". Journal of the Chemical Society (Resumed): 3623. doi:10.1039/jr9530003623.
- ↑ Boyland, E.; Sims, Peter (1954). "The oxidation of some aromatic amines with persulphate". Journal of the Chemical Society (Resumed): 980. doi:10.1039/jr9540000980.
- ↑ Behrman, E. J. (1988). "The Persulfate Oxidation of Phenols and Arylamines (The Elbs and the Boyland-Sims Oxidations)". Org. React. 35: 421–511. doi:10.1002/0471264180.or035.02. ISBN 0471264180.
- ↑ Boyland, E.; Sims, P.; Williams, D. C. (1956). "The oxidation of tryptophan and some related compounds with persulphate". Biochem. J. 62 (4): 546–50. PMC 1215958. PMID 13315210. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=1215958.
- ↑ Behrman, E. J. (1992). "The ortho-para ratio and the intermediate in the persulfate oxidation of aromatic amines (the Boyland-Sims oxidation)". J. Org. Chem. 57 (8): 2266. doi:10.1021/jo00034a016.