Caleb University

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ile- ẹkọ giga Caleb jẹ ile-ẹkọ giga aladani kan ti o wa ni Imota, Lagos, Nigeria . [1][2]

Itan Ile-ẹkọ giga Caleb ti bẹrẹ lati ọdun 1986 nigbati Ọmo-oba Ọladega Adebogun dá ilé-ìwé nọsìrì ati pramari ni aarin Ilu Eko .

Itayo ninú eto-ẹkọ àti iwà dada ti won di kó àwon omo ilé-ìwé náà mú ki òpòlopò òbí fé mú omo won si ilé-ìwé naa. Awọn obi tun bẹrẹ sí fe kí wón da ilé-ìwé Sekondri kalè, ti yó sì tayo nínú ètò Èkó àti ninú kíko àwon omo ní iwà rere. Eyi, lomu ki wón da International College ni Magodo GRA, Lagos, sílè ni 1995.

Kọlẹji naa jé ibi ti òpòlopò omo to pari lati ilé-ìwé primari náà n lo.

Laarin ọdun diẹ twón idasileitayi awon omomọ ile-iwe kọlẹji ni awọn idanwo Iwe-ẹri Junior ati Senior WAEC (JSCE/SSCE) gbé ilé-ìwé naa sókè laarin elegbe rè, o si mu ki o wà laara awon ilé-ìwé Sekondiri ti awon eniyan yìn orúko rè ní Nàìjíríà

Prince Adebogun ro ninú ara rè láti da ilé-èkó giga kalè, ni odun 2005, Wón ra ilè tí o to ékà méjì. Ni osù kokanla odun kanna, ajo NUC- SCOPU dan won wo, wón tún tún won danwo ni osù karun odun 2006. Léyìn odun kan, ìjoba fún wòn Caleb University láyè láti sisé, Yunifásitì náà si bèrè isé ní odun 2008.

Awọn ẹye[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A fun Caleb university ni ami èye fún International Outstanding University with quality education and moral standards award

Awọn itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Caleb University". Ranking & Review. August 11, 2022. Retrieved September 13, 2022. 
  2. Contributor, Pulse (January 21, 2020). "Student". Pulse Nigeria. Retrieved September 13, 2022. 

[1]

  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :0