Jump to content

Centre International des Civilisations Bantu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àjọ Centre International des Civilisations Bantu (CICIBA) àjọ ìbílè tí ó wà ní Libreville, Gabon. Wọ́n da kalẹ̀ lábé ìdarí Ààrẹ Gabon Omar Bongo ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kínní, ọdún 1983, wọ́n sì da àjọ náà kalẹ̀ láti kọ́ nípa àwọn ènìyàn Bantu.

Ní ọdún 2012, wón kéde pé wọ́n ma tún ilé tí àjọ náà ń lò kọ́, lẹ́yìn tí wọ́n pá tì ní 1988 nítorí àìsówó.[1]

Àwọn orílẹ̀ èdè tí ó jé ara àjọ náà ni: Angola, Cameroon, Central African Republic, Comoros, Republic of the Congo, Democratic Republic of Congo, Equatorial Guinea, Gabon, Rwanda, São Tomé and Príncipe, and Zambia.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "The CICIBA soon to be renovated - Gabonews English". en.gabonews.com. Archived from the original on 13 December 2013. Retrieved 6 June 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Jeune Afrique (2014-09-03). "Le Centre international des civilisations bantoues, un mirage africain – Jeune Afrique". JeuneAfrique.com (in Èdè Faransé). Archived from the original on 2017-05-19. Retrieved 2020-06-05.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)