Chanda Rubin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Chanda Rubin
Chanda Rubin playing in the U.S. Open Champions Team Tennis September 9, 2010
Orílẹ̀-èdèÀwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan United States
IbùgbéLafayette, Louisiana, US
Ọjọ́ìbíOṣù Kejì 18, 1976 (1976-02-18) (ọmọ ọdún 48)
Lafayette, Louisiana, U.S.
Ìga1.68 m (5 ft 6 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fàAugust 1991
Ọwọ́ ìgbáyòRight-handed (two-handed backhand)
Ẹ̀bùn owóUS$4,469,990
Ẹnìkan
Iye ìdíje399–254
Iye ife-ẹ̀yẹ7 WTA, 2 ITF
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 6 (April 8, 1996)
Grand Slam Singles results
Open AustrálíàSF (1996)
Open FránsìQF (1995, 2000, 2003)
Wimbledon4R (2002)
Open Amẹ́ríkà4R (1992, 1995, 2002)
Ẹniméjì
Iye ìdíje226–160
Iye ife-ẹ̀yẹ10 WTA, 3 ITF
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 9 (April 15, 1996)
Grand Slam Doubles results
Open AustrálíàW (1996)
Open FránsìSF (2003)
WimbledonSF (2002)
Open Amẹ́ríkàF (1999)
Last updated on: December 11, 2009.

Chanda Rubin (ojoibi February 18, 1976) je agba tenis ara Amerika to ti feyinti. O gba ife-eye awon idije WTA Tour enikan meje, ipo re to gajulo ni World No. 6 ni April 8, 1996, leyin igba to de ilajidopin ni Open Australia 1996. Bakanna Rubin de ipo World No. 9 ninu idije enimeji, o gba Open Australia 1996 pelu Arantxa Sánchez Vicario.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]