Jump to content

Charles Olúmọ

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Charles Olúmọ tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Àgbákò ṣùgbọ́n tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Abudul Salam Sànyàolú (ti a bi ni Oṣu Keje ọdun 1923 o si ku ni Oṣu Kẹwa Ọjọ 31, Ọdun 2024) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìlú Abẹ́òkútaìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Nínú sinimá àgbéléwò èdè Yorùbá tí ó jẹ́ abala Nollywood ni ó ti gbajúmọ̀.

Charles Olúmọ
Ọjọ́ìbíAbudul Salam Sànyàolú
Orúkọ mírànÀgbákò
Ọmọ orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iṣẹ́Osere

Iṣẹ́ tíátà rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àgbákò bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà lọ́dún 1953 ní ilé ìjọsìn, The Apostolic Church ni ìpínlẹ̀ Èkó.[1]

Àwọn Ìtọ́kasí ìta

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "My Father used charm on me to make me lose interest in Acting – Charles Olumo Agbako". Sahara Weekley. 2015-10-27. Retrieved 22 January 2017.