Chidi Chike Achebe
Ìrísí
Chidi Chike Achebe | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Chidi Chike Achebe 24 Oṣù Kàrún 1967 Enugu, Nigeria |
Ẹ̀kọ́ | Harvard School of Public Health |
Iṣẹ́ | Physician, CEO of AIDE |
Chidi Chike Achebe (tí a bí ní ọjọ́ 24 oṣù May, ọdún 1967) jẹ́ oníṣègùn. Òun ni alagá àti olùdarí àgbà fún AIDE (African Integrated Development Enterprise). Òun ni ọmọ kẹta ti Chinua Achebe, ìyẹn òǹkọ̀wé tó kọ àwọn ìwé bí i Things Fall Apart (1958); "No Longer at Ease" (1960); àti "Arrow of God" (1964).[1]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Ezenwa-Ohaeto (1997). Chinua Achebe: A Biography.. Bloomington: Indiana University Press. p. 280. ISBN 9780253333421. https://archive.org/details/chinuaachebebiog0000ezen/page/280.