Chidinma

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Chidinma Ekile)
Chidinma
Chidinma Ekile
Background information
Orúkọ àbísọChidinma Ekile
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiMs. Kedike
Ọjọ́ìbí2 Oṣù Kàrún 1991 (1991-05-02) (ọmọ ọdún 32)[1][2]
Ketu, Kosofe, Lagos State
Ìbẹ̀rẹ̀Ikorodu, Lagos State
Irú orinAfropop
Occupation(s)Singer, songwriter
Years active2011 – present
LabelsCapital Hill (former)[3]
Associated acts

Chidinma Ekile (ojoibi 2 May 1991), tò gbájùmọ̀ pẹ́lù òrùkọ̀ òrì-ìtágé rẹ́ ńì Chidinma, jẹ́ akọ̀rìń átì òlòrìń àrá ìlẹ́ Naijiria. Ńì ọ̀dùń 2010 ńì íràwọ̀ rẹ́ kòkò yò ńìgbá tò gbá ìpò kìńì lòrì étò tèlìfìṣáń tò ń jẹ́ Project Fame West Afrìká.

Íbẹ́rẹ Ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Chidinma Ekile wọ̀ń bì ńì ádùgbò Kétù ńì Kòṣọ̀fẹ́ ńì ìpìńlẹ́ èkò . Ṣùgbọ̀ń áwọ̀ń òbírẹ́ wá lá tì ìpìńlẹ́ ìmò. Chidinma jẹ́ ọ̀mọ̀ kẹ́fá ńìńù ọ̀mọ̀ mèjè tì áwọ̀ń òbì ẹ́ bì. Chidinma gbè pẹ́lù bábà tò mòjùtò ọ̀mọ̀, atì ìbẹ́ lòtí kọ̀ òrìń látí ọ̀mọ̀ ọ̀dùń mèfá.[10]Nì ìgbá tì ò dì ọ̀mọ̀ ọ̀dùń mẹ́wá, òdárápọ̀ mọ̀ ẹ́gbẹ́ ákọ̀rìń ńì ìlè ìjọ̀sìń.[11] Chidinma lọ̀sì ìlè ìwè gírámà tì ò wá ńì kètù ńì ìbí tì òtì bẹ́rẹ̀ Ile iwe ákọ̀bẹ́rẹ̀ átì gírámá tò tì párì. Lẹ́yìń Igba tì òpárì ílè iwe giga oni iwe mẹ́fá , ò darapọ̀ mọ̀ awọ̀ń Ti wọ̀ń gbe owo si ta(Promoter) tì ò si dárá pọ̀ mọ̀ Fame West Africa . Chidinma kọ̀kọ̀ lọ̀ ka iwẹ́ iroyin ṣùgbọ̀ń ò pada lọ̀ká sociology Ni Ile ẹ́kọ̀ giga fásìtì Èkò. Ni Igba ti [12] Chidinma, ńìńù ìbèré fòhùń(interview) pẹ́lù YNaija, ósọ̀fùń wọ̀ń pe kinọ̀rìń ò ki ṣè tọ̀hùń Sùgbọ̀ń ńi Igba ti ohun ti jà we bọ̀rì ńìńù ìdìjè òrìń.



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Akinloye, Dimeji (26 July 2012). "Close Up on Stars – Chidinma". Hip Hop World Magazine. Archived from the original on 2 May 2014. Retrieved 2 May 2014. 
  2. "Chidinma Wins Best West African (Female) Category at the 2012 KORA Awards". Bella Naija. Retrieved 2 May 2014. 
  3. "Would Chidinma Dump Capital Hill Records?". Global Excellence. 29 January 2014. Archived from the original on 2 March 2014. Retrieved 21 February 2014.