Jump to content

Chidozie Kennedy Ibeh

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Chidozie Kennedy Ibeh
Member of the Imo State House of Assembly
ConstituencyObowo
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí25 June 1976
AráàlúNigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressive Congress
Alma materEnugu State University of Science and Technology, Abia State University
OccupationPolitician, lawyer

Chidozie Kennedy Ibeh jẹ́ olóṣèlú àti agbẹjọ́rò ọmọ orile-ede Nàìjíríà . O je omo ile ìgbìmò asofin ìpínlè Imo to n sójú àgbègbè idibo ìpínlẹ̀ Obowo. [1]

Ìrìnàjò re nínú

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

O je olori ile igbimo asofin ipinle Imo labe egbe oselu All Progressives Congress titi di igba ti o fi fi ipo sile lodun 2022.

Kennedy jẹ ẹlẹ́ṣin Onigbagbọ.