Chigozie Wisdom
Chigozie Wisdom | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Chigozie Wisdom Anyanwu |
Ọjọ́ìbí | 24 Oṣù Kejì 1983 |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Imo State |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Instruments | Vocals |
Years active | 2010–present |
Chigozie Wisdom Anyanwu tí wón bí ní ọjọ́ kẹfàdínlọ́gbọ̀n oṣù Kejì ọdún 1983 jé olóri èmí tí ilẹ̀ Nigeria, adarí àwon olórín, àti akọ orin silẹ. [1][2][3] Ó gbé orin àkọ́kọ́ rè jáde ní odún 2010 tí àkọ́lẹ́ rè jé “ Ẹ yin Olúwa "(Praise Adonai) àti album àkọ́kọ́ “ Ẹ forí balẹ̀ ( Bow Dow) àti E sìn ín ( Worship Him).
Ìgbésíayé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bíi Chigozie Wisdom ní ọjọ́ 24 February 1983 he originally hails from imo state Nigeria. Ó parí ilé-ẹ̀kọ́ giramá rẹ̀ ní Folamo High School, Lagos State and acquired his Bachelor's Degree from Lagos State University, Nigeria.[5]
Iṣé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Chigozie Wisdom started his musical career at a very tender age with the children’s choir. By the age of seven he had become a choir leader in the children’s department. His first album "Bow Down and Worship Him" was released in April, 2017 and comprised 22 tracks including "Kumama", "Messiah" and "Naba Katuwo".[6]
On 3 October 2022, he was among the musicians featured at the 5th edition of the Worship4Change Concert alongside Moses Bliss, Nathaniel Bassey, Victoria Orenze and others.[7][8][9]
Àwo-orin
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year Released | Title | Details | Ref |
---|---|---|---|
2020 | No Limits |
|
[10] |
2017 | Bow Down and Worship Him |
|
[11] |
Kekeke
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Ona Iye (2022)[12]
- Bid Me To Come (2022)[13]
- I'll Be There (2021)
- Everything That Has Breath (2021)
- Ese Gan Ni (2020)[14]
- Pada Wale (2017)
- My Commitment (2017)
- I am that I am (2015) [15]
- Praise Adonai (2010)
Awards àti yíyan
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]In May 2023, Chigozie Wisdom was given an honorary citizen award from the State of Georgia in the United States of America.[16][17]
Ìgbésí ayé ara ẹni
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Chigozie Wisdom ṣe ìgbéyàwó ó sì bí ọmọ mẹ́ta.[18] He lives in Lagos State, Ó ń gbé ní ìlú Èkó tí ó wà ní orílé èdè Nàìjíríà.[19]
Awọn Ìtọ́kàsí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "At ‘Shabach Night’, Senwele Jesu, Chigozie, Alawiye-Aluko, others thrill with unusual praise". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-12-12. Retrieved 2023-05-13.
- ↑ wazobiatimes (2021-07-11). "Ministers Chigozie Wisdom, Psalmos, Kingdom Ambassador Temitope Omotayo and Others Ministered at True Worship Explosion 2021". Breaking Down Boundaries with Information (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2023-05-14. Retrieved 2023-05-13.
- ↑ "Bow Down & Worship Him by Chigozie Wisdom". www.top-charts.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-13.
- ↑ "Bow Down & Worship Him by Chigozie Wisdom". www.top-charts.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-13.
- ↑ Gospelrant (2022-07-29). "Chigozie Wisdom | Biography, Songs & Wife « Gospel Rant". Gospel Rant (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-13.
- ↑ Bow Down & Worship Him by Pst Chigozie Wisdom (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), 2017-04-14, retrieved 2023-05-13
- ↑ "Worship4Change featuring Nathaniel Bassey, Chigozie Wisdom and others to raise N75m for indigent children". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-09-25. Retrieved 2023-05-13.
- ↑ Rapheal (2022-09-24). "Worship4Change to raise N75m for indigent children". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-13.
- ↑ Partners, N. M. (2022-09-23). "Worship4Change to Raise N75m for Indigent Children with Special Needs, Holds Benefit Concert Oct. 3 in Lagos". Nairametrics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-13.
- ↑ No Limits (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), 2020-05-02, retrieved 2023-05-13
- ↑ Pst Chigozie Wisdom - Bow Down & Worship Him | Down In The Valley - Music, Movies, Minneapolis & More (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), retrieved 2023-05-13
- ↑ Radio, Worshipculture (2022-04-11). "[Video] Ona Iye By Chigozie Wisdom". Worshipculture Radio (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-13.
- ↑ "Chigozie Wisdom Discography". Spotify (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-13.
- ↑ ekpenyong, Ebenezer (2019-12-22). "Chigozie Wisdom Drops New Video 'Ese Gan Ni'". Premium9ja (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-13.
- ↑ I Am That I Am By Zion Voices - Led by Chigozie Wisdom (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), retrieved 2023-05-13
- ↑ Rapheal (2023-04-28). "Atlanta Georgia honours Nigerian gospel singer, Chigozie Wisdom". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-13.
- ↑ Aliyu, Abdullateef (2023-05-06). "US awards honorary citizenship to Nigerian gospel artiste". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-13.
- ↑ "Chigozie Wisdom Biography: Age, Wife, Children & Net Worth - Famous Today" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2023-10-17. Retrieved 2023-10-28.
- ↑ "My marriage...with Chigozie Wisdom". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-01-14. Retrieved 2023-05-13.
tí wón bí ní ọjọ́ kẹfàdínlọ́gbọ̀n oṣù Kejì ọdún 1983 jé olóri èmí tí ilẹ̀ Nigeria, adarí àwon olórín, àti akọ orin silẹ. Ó gbé orin àkọ́kọ́ rè jáde ní odún 2010 tí àkọ́lẹ́ rè jé “ Ẹ yin Olúwa "(Praise Adonai) àti album àkọ́kọ́ “ Ẹ forí balẹ̀ ( Bow Dow) àti E sìn ín ( Worship Him).