Chioma Udeaja

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Chioma Udeaja
No. 14 – First Bank
PositionPower forward / Center
LeagueNPL
Personal information
Born29 Oṣù Kẹfà 1984 (1984-06-29) (ọmọ ọdún 39)
Lagos, Nigeria
NationalityNigerian
Listed height6 ft 3 in (1.91 m)
Career information

Chioma Udeaja (tí a bí ní June 29, 1984) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alájùsáwọ̀n, tó gbá bọ́ọ̀lù náà fún First bank àti ẹgbẹ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ọmọbìnrin yìí ni a tún mọ̀ sí Elephant Girl.[1]

Iṣẹ́ rẹ̀ lágbàáyé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó kópa nínú Women's Afrobasket tó wáyé ní ọdún 2017. [2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]